Be Strong In The Lord

THE SEED
Finally, my brethren, be strong in the Lord and in the power of His might. Ephesians 6:10

God has given us everything we need to be victorious over Satan, through Jesus Christ. It is up to us to strengthen ourselves in the Lord and in the power of His might. The Holy Spirit was the power source for Jesus, while He lived in a human body and He is also the source of power for us. The Holy Spirit is our Helper, which means that He does not force us to do anything, but He helps us when we ask Him to and gives us the strength we need in every situation. Until the crucifixion, Jesus was never separated from His Father and they always had a close relationship. We should follow Jesus’ example in being obedient, praying and following God’s direction all the time. By praying, studying and meditating upon the Word of God, by praising and worshiping the Lord, we strengthen our “inner man of the heart” and we are able to overcome the strategies of the devil.

BIBLE READING: COLOSSIANS 2

PRAYER: Lord, please help me to remember that You did all it takes for me to be strong and be able to walk in Your power. Lord please give me a deeper understanding of Your Word so that I may be strengthened, take courage and know how much You love me, in Jesus Christ’s name. Amen.

JẸ ALAGBARA NINU OLUWA

IRUGBIN NAA
Nikẹhin, ará mi, ẹ jẹ alagbara ninu Oluwa ati ninu agbara ipá rẹ̀. Efesu 6:10.

Ọlọrun ti fún wa ní ohun gbogbo tí a nílò láti ṣẹgun Satani nípasẹ̀ Jesu Kristi. O fun wa lati lagbara ninu Oluwa ati ninu pagbara Rẹ. Ẹ̀mí mímọ́ ni orísun agbára fún Jésù, nígbà tí ó wà nínú ara ènìyàn àti pé òun náà ni orísun agbára fún wa. Ẹ̀mí mímọ́ ni Olùrànlọ́wọ́ wa, èyí tí ó túmọ̀ sí pé kò fi ipá mú wa láti ṣe ohunkóhun;ṣùgbọ́n Ó ń ràn wá lọ́wọ́ nígbà tí a bá béèrè lọ́wọ́ rẹ̀, ó sì ń fún wa ní agbára tí a ní lò ní gbogbo ọnà .Titi di iku ori igi agbelebu, Jesu ko yapa kuro lọdọ baba Rẹ ati pe wọn ni ibasepọ timọtimọ. A gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jésù nínú jíjẹ́ eniti o ngbọràn, tí o ngbàdúrà ti o sí ntẹ̀lé ìtọ́sọ́nà Ọlọ́run nígbà gbogbo. Nípa gbígbàdúrà, kí kẹ́kọ̀ àti ṣíṣe àṣàrò lórí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, nípa yíyin àti jí jọ́ sìn fun Olúwa, a nfún “èda inú ati ọkàn-àyà” wa l’ókun, láti lè borí àwọn ọgbọ́n èṣù.

BIBELI KIKA: Kolose 2

ADURA: Olúwa, jọ̀wọ́. ran mi lọwọ lati ranti pe Ẹ ṣe gbogbo ohun ti o wa ni ipa yin fun mi lati rin ninu agbara Rẹ. Oluwa jọwọ fun mi ni oye ti ọrọ rẹ ti o jinlẹ̀ ki n le ni okun, ki n ni igboya lati mọ bi O ti fẹràn mi to, ni oruko Jesu Kristi. Àmín

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *