BE TRAINED
THE SEED
“Seest thou a man diligent in his business? He shall stand before kings; He shall not stand before mean men.” Proverbs 22:29.
When you see someone that is good at what he or she does, it is most likely that the person has an inherent ability, or he/she has been trained in it.
A professional is defined as someone who displays high levels of expertise and efficiency in their work, and it is inherent to say that someone addressed as a professional must have undergone various trainings, for him or her to have attained such a height in his or her career/profession. Whether in the spiritual or physical engagements, one needs to accept being trained in what you do. Submit yourself to being tutored.
The disciples were under the tutelage of Christ Jesus before they were later called the Apostles. Training takes a lot of effort and dedication, but it helps you to acquire wisdom, knowledge and understanding to become a master of your activities.
Practice your songs, read, and memorise that Bible verse repeatedly, practice how to evangelise, ask for and accept corrections, be trained in the work of the ministry, be trained in counselling. Follow the instructions of the Holy Spirit, learn from God-inclined people and you shall be empowered through receiving training.
PRAYERS
Lord, help me to maximise and utilise my training period effectively in Jesus name. Amen. BIBLE READINGS: Proverbs 4:1-13
DÀBÍ ENITI O NÍ ẸKỌ
IRÚGBÌN NÁÀ
“Ìwo rí eniyan tí o nfi aisemele ṣe ìṣe rẹ? òun o duro n’iwaju awọn ọba; oun kí yíó dúró níwájú àwọn ènìyàn lásán.” Iwe owe 22:29
Tí o ba ri ẹnití o jafafa ninu ohun ti o nṣe, o ṣe e ṣe kí irú ènìyàn bẹ jogún ìmọ nínú iṣẹ tí o kọ. A kọ ṣe mọ ṣe ní irú ènìyàn náà, ẹnití a nṣe àpèjúwe rẹ, tí o nṣe àfihàn àti amọdun jù nínú ohun ti o kọ.
A lè sọ nipa irú ènìyàn bẹ, bí ẹnití o ti la orisirisi idanileko kọjá, kí o tó lé dé ipele ti o ga nínú iṣẹ tí o yan laa yo .
Yálà nínú èmi tàbí nínú ará, nínú ohun tí a bá fẹ́ṣe, anilati gbà, latí ní ẹkọ rẹ: yọnda ará rẹ fún idanileko. Awon ọmọ ẹhìn wá ní abé idanileko kí a tó pé wọn ní àpọsítélì. Iṣẹ kíkọ gbà òpòlopò igbiyanju atí ifọkansi, lẹhin rẹ o o gbà ọgbọn, ìmọ àti òye láti dì ọgá nínú àwọn ojúṣe rẹ.
Ṣe àgbéyẹ̀wò ninu orin, ká akosori nínú ẹsẹ bíbélì leralera; kọ bí a ti nṣe ikede lati jere ọkàn, bere fún, kí o sí gbà ìbáwí. Kọ ẹkọ nínú iṣẹ ìjọ, gbà ẹkọ nínú iṣẹ igbani niyanju. Tẹle imọran emi mímó, kọ ẹkọ láti ọdọ àwọn ènìyàn Ọlọrun, ao sì sọ ọ di alágbára nípa ẹkọ.
ADURA
Oluwa rán mi lọwọ láti lo àsìkò idanileko àti ikẹkọ mi daradara ni orúkọ Jésù Amin
BIBELI KIKA: Owe 4:1-13