Can You Trust The Bible?

THE SEED
Keep this Book of the Law always on your lips; meditate on it day and night, so that you may be careful to do everything written in it. Then you will be prosperous and successful.  Joshua 1:8

It matters what you think about the Bible. Some individuals believe that it is simply an old book that is no longer relevant. However, because it was inspired by God, it is actually the most amazing book ever produced. He inspired words to be written by people. The Bible is a timeless book that contains God’s universally applicable truth. It is error-free and has always been under His protection. The Bible reveal who God is, how He has dealt with humanity since the beginning of time, and the future changes that He has promised. Christians are quick to proclaim the importance of the Bible, but our deeds reveal our true beliefs. If we don’t read the Bible often, it will be clear from our behaviour that we don’t value it and don’t need to hear from God often. David claimed in Psalm 19 that God’s Word is more delicious than honey (Psalm 19:10). Would you concur with that? If not, be reassured that the more you read and study it, the sweeter and more appealing His Word becomes.

PRAYER
Give me the grace to meditate in your words day and night, let your word directs my path in Jesus name, Amen.
BIBLE READINGS:  2 Peter 1:16-21

  ǸJẸ́ O GBẸ́KẸ́LE BÍBÉLÌ?

IRUGBIN NAA
Pa Ìwé Ofin yìí mọ́ ní ètè rẹ nígbà gbogbo; máa e ààrò lé e lórí lọ́sàn-án àti lóru, kí ẹ lè ọ́ra láti e gbogbo ohun tí a kọ sínú re. Lẹhinna ni e o do alabukunfu ati alaeyọri. (Jóúà 1:8)

Ohun ti o ro nipa Bibeli se Pataki. Diẹ ninu awọn eniyan gbagbọ pe o jẹ iwe atijọ ti ko wulo mọ. Bí ó ti wù kí ó rí, nítorí pé Ọlọ́run mí sí i, ó jẹ́ ìwé àgbàyanu jù lọ tí a tíì ṣe rí. Ólorun mí sí àwọn oro tí o lo awọn ènìyàn lati  kọ. Bíbélì jẹ́ ìwé AYERAYE to ko ni akoko kan Pato ti won Koo, eyití o ni otito ólorun ti o la GBOGBO aye ja. Ko ni aṣiṣe ati pe o wa labẹ aabo Rẹ nigbagbogbo. Bíbélì jẹ́ ká mọ irú ẹni tí Ọlọ́run jẹ́, bó ṣe ń bá edá ènìyàn lò láti ìbere pepe ayé, àti àwọn ìyípadà ọjọ́ iwájú tí Ó ṣèlérí. Awon Onigbagbo ma n Yara lati so Pataki bibeli ṣugbọn ise ati iwa wa lo n fi otito igbagbo wa han. Ti a ko ba ka Bibeli nigbagbogbo, yoo han lati inu iwa wa pe a ko ni idiyele rẹ ati pe a ko nilo lati gbọ lati ọdọ Ọlọrun nigbagbogbo. Dafidi sọ ninu Orin Dafidi 19 pe Ọrọ Ọlọrun dun ju oyin lọ (Orin Dafidi 19:10). Ṣe iwọ faramo be? Bí bẹ́e kọ́, jẹ́ kí o fọkàn bale pé bí o ṣe ń kà á tí o sì ń kẹ́koọ́ rẹ̀ síi, bẹ́e náà ni oro re  yóò ṣe dùn tó, tí ó sì fani mọ́ra síi.

ADURA
Fun mi ni oore-ọfẹ lati ṣe àṣàrò ninu awọn ọrọ rẹ lọsan ati loru, jẹ ki ọrọ rẹ ṣe itọsọna ọna mi ni orukọ Jesu, Amin.
BIBELI KIKA: 2 Pétérù 1:16-21

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *