DO NOT FIGHT YOUR CO-BRETHREN

DO NOT FIGHT YOUR CO-BRETHREN

THE SEED
“Every kingdom divided against itself is brought to desolation; and a house divided against a house falleth.” Luke 11:17 KJV

The opening Bible verse followed an incident where Jesus cast out a demon from a man who was mute. Some accused Him of doing this by the power of Beelzebub, while others sought signs from heaven. This lack of unity reflect the challenges we often see in the body of Christ today. Sadly, some churches and believers isolate themselves, discriminate, and harbor animosity toward others. Instead of being united in faith and love, we often see hatred, backbiting, and disunity among Christians. Yet, the Bible calls us to unity. If we as Christians would come together, united in heart and prayer, we could bring healing and transformation to the world. Say no to disunity and division! Allow the love of God to reign in your heart and dwell together in peace and harmony. Let us be one body, one spirit, and one family under God, standing firm together against the forces of evil.

BIBLE READING: Luke 11:14-27
PRAYER: Father of light, guide us as Christians to walk in Your love and unity. Help us to stop all fighting and live in harmony in Jesus’ name, Amen.

 

MAṢE BA AWỌN ARAKUNRIN RẸ JA

IRUGBIN NAA
“Gbogbo ìjọba tí ó ya ara rẹ̀ ní ipá, ni a ń sọ di ahoro; ilé tí ó sì ya ara rẹ̀ nípá yóò wó.” Luku 11:17 KJV

Ẹsẹ Bíbélì tó bẹ̀rẹ̀ yii jeyo lehin ìṣẹ̀lẹ̀ kan níbi tí Jésù ti lé ẹ̀mí esu jáde lara ọkùnrin kan tó yadi. Àwọn kan fẹ̀sùn kàn án pé ó ń ṣe èyí nípasẹ̀ agbára Beelsebulu, beeni àwọn mìíràn n wá àmì láti ọ̀run. Aini ìṣọ̀kan yìí safihan àwọn ìpèníjà tí a sábà máa ń rí nínú laarin awa Kristeni lónìí. Ó bani nínú jẹ́ pé, àwọn ṣọ́ọ̀ṣì kan àtàwọn onígbàgbọ́ kan ya ara wọn sọ́tọ̀, wọ́n ń ṣe ẹ̀tanú, wọ́n sì ń ni ìkórìíra sí àwọn ẹlòmíràn. Dípò kí a wà ní ìṣọ̀kan nínú ìgbàgbọ́ àti ìfẹ́, a sábà máa ń rí ìkórìíra, isoro ehin, àti aìṣọ̀kan láàárín àwọn Kristẹni. Síbẹ̀, Bíbélì pè wá sí ìṣọ̀kan. Bí àwa Kristẹni bá pé jọ, ní ìṣọ̀kan nínú ọkàn kan pelu àdúrà, a lè mú ìwòsàn àti ìyípadà rere bá ayé. E je ki a fi aisokan ati ipinya laarin onigbagbo bu! Ki a gba ife Olorun laaye lati joba ninu okan wa ki a si maa gbe papo ni alafia ati isokan. Jẹ ki a jẹ ara kan, ẹmi kan, ati idile kan labẹ Ọlọrun, ti o duro ṣinṣin papọ lodi si gbogb ipa satani.

BIBELI KIKA: Lúùkù 11:14-27
ADURA: Baba imole, dari wa gege bi Kristeni lati rin ninu ife ati isokan Re. Ran wa lọwọ lati da gbogbo ija duro ki a si gbe ni isokan ni orukọ Jesu. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *