DON’T ALLOW SITUATIONS TO CHANGE THE PERSON YOU ARE!

DON’T ALLOW SITUATIONS TO CHANGE THE PERSON YOU ARE!

THE SEED 

MAY 24 TUE 2022

“Put away your sword, Jesus told him. Those who use the sword will die by the sword.”  Matthew 26:51-52 NLT 

The above scripture is a verse that shared one of the incidents that occurred when Jesus  was arrested and going to die for us. It was an agonising and crucial time for Jesus. Yet Jesus did  not allow this huge burden he was about to carry change His personality. He maintained His  character to the end. His love and compassion were shown on the slave whose ear was slashed  off by putting it back together. He still had the heart to bring correction to the disciples.  Throughout this entire episode of Jesus’ crucifixion, not at any time did the Bible mention that  he allowed his pain and suffering to get the better of Him. Jesus is our example and role model. If He can go through all the sufferings without changing His person, we do not have any excuse  of losing our cool and personality just because we found ourselves in some unpalatable  situations. There are many Christians that tend to easily exhibit some demeaning behaviours  such as anger, quarrelling, swearing, corruption, and more, just to defend themselves in the  face of opposition without even thinking about it. Remember that the personality of Jesus never  changed. So don’t allow the person you are as a child of God to change whenever you find  yourself in any unpleasant situations. 

PRAYER 

Father, help me to always remember who I am in You at all times in Jesus name. Amen. BIBLE READINGS: 1 Peter 4:12-13 

MASE JEKI OHUNKOHUN YI O PADA KURO NINU OHUN TI O JE. IRUGBIN NAA 

“Fi ida re si ipo re: nitoripe gbogbo awon ti o mu ida ni yio ti ipa ida segbe. Matteu 25:51- 52 

Iwe mimo ti a ka, je ese ti o fi ikan ninu awon ohun ti o sele han, nigbati a mu Jesu nlo si  ibi ti yio ti ku fun wa. O je asiko irora ati iwoyaja fun Jesu. Ranti bibeli so pe Jesu wa, ninu ogba  Gestimani, saaju asiko yi ti o ngbadura si baba nipa wakati yi, nitoripe o daamu ninu okan re. A  le so pe asiko ti o le gidi ni fun un, bi bibeli se ko. Sibe Jesu ko gba ki eru wuwo ti o fe gbe ki o yi  iru eni to je pada. O mu ipinu re l’ori iwa Re. Ife re ati ibanikedun Re, fi han lara eru ti won ge eti  re; nipa lile eti naa pada. O tun ni okan lati ba awon omo ehin re wi ati lati ko won ni otito pataki  nipa aye ni gbogbo asiko ijiya ati iku Re lori igi agbelebu, ko si gba ti Bibeli so pe o gba irora ati  ijiya laaye lati ba ra je. Jesu je apere ati eniti a le farawe, ti o ba le farada irora lai yi iseda re  pada; a ko ni awawi lati s’iwa hu nitoripe a ba ara wa ninu iporuru. Opo Kristeni ni won maa nsi  iwa hu ti won ba wo inu wahala: bi i ibinu, ija, ibura iwa ibaje ati be e lo: lati le e yo ara won kuro  ninu idojuko ti won ni, lai ro ohun ti won nse. 

Ranti pe iwa Jesu ko yipada. Nitori idi eyi mase gba ki iru eniyan ti o je bi omo Olorun ki  o yipada, nigbakugba ti o ba ba ara re ninu idojuko ti ko te o lorun. 

ADURA 

Baba, ranmilowo lati ma a ranti iru eniti mo je ninu Re nigbagbogbo ni oruko Jesu Amin.  BIBELI KIKA: 1 Peter 4:12-13 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *