Don’t Lose Your Sainthood Over Lack

THE SEED
“Oh, fear the Lord, you His saints! There is no want to those who fear Him. The young lions lack and suffer hunger, But those who seek the Lord shall not lack any good thing.” Psalms 34:9-10 NKJV

As believers, we are saints of God’s Kingdom. The scripture above is directed at Saints and not unbelievers. You can ask ‘ I thought Saints are perfect people, why then are the Saints asked to fear God?’ yes it is true that Saints are perfect people of God but as long as we are still living in the world of sin, we are exposed to errors of the wicked which can tarnish our sainthood which we received through grace from our Lord Jesus. More than ever it is most important to be deliberate about allowing the fear of God to prevail over our needs so that we don’t allow lack or difficult situations to push us into the error of the wicked. The Lord is true to His words, he will take care of us. The world is full of lack, distress and anxiety but if only we fear God in our deeds and actions and not be led into evil by any means, then His word will come through for us as said by the Psalmist- Oh, fear the Lord, you His saints! There is no want to those who fear Him. The young lions lack and suffer hunger, But those who seek the Lord shall not lack any good thing.

PRAYER
Lord, may I not lose the kingdom of heaven because of lack.
BIBLE READINGS:  Psalms 34:9-17

  MASE PADANU IWA MIMO RE NITORI AINI

IRUGBIN NAA
“Áà, ẹ berù Olúwa, eyin ènìyàn mímo re! Ko si aini fun awon ti o beru Re. Àwọn ọmọ kìnnìún a ma se aláìní, ebi a sì ma  pa won,ùgbon àwọn tí ń wá Olúwa kì yóò e aláìní ohun rere kan.”

Gege bí onígbàgbo, ẹni mímo ti Ìjọba Ọlorun ni wá. Iwe-mimọ ti o wa loke wa fun awọn eniyan mimọ kii ṣe awọn alaigbagbọ. O le beere pe ‘Mo ro pe awọn eniyan mimọ jẹ eniyan pipe, kilode ti a fi beere fun awọn eniyan mimọ lati bẹru Ọlọrun? Beeni, looto ni wipe àwọn ènìyàn mímo je eni pipe Ólorun ṣugbọn niwongba ti a ba si n gbe ninu aye eṣe yi, a ko le sai ni asise nípase awon ènìyàn búburú tí ó lè ba iwà mímo wa je, eyi ti a rigba nipa oore-ofe ti Oluwa was Jesu. Ju ti ìgbàkigbà rí lọ ó ṣe pàtàkì jùlọ láti mo o mo gba ìberù Ọlorun laye láti borí àwọn àìní wa kí a má baà je kí àìní tàbí isoro wa ti wa sínú àṣìṣe àwọn ẹni ibi. Oluwa je olooto si oro Re, yio toju wa. Ayé kún fún àìní, ìdààmú àti àníyàn ṣùgbon tí a bá berù Ọlorun nínú iwa àti ìṣe wa tí a kò sì mú wọn lọ sínú ibi lonàkọnà, nígbà náà ni oro Re yóò se wá fún wa gege bí Onísáàmù ti sọ- Ó, ẹ berù Olúwa, enyin mimo Re! Ko si aini fun awon ti o beru Re. Àwọn ọmọ kìnnìún a maa se aláìní, ebi a  sì ma pa won, ṣùgbon àwọn tí ń wá Olúwa kì yóò ṣe aláìní ohun rere kan.

ADURA
Oluwa, ma je kin padanu ijoba orun nitori aini
BIBELI KIKA: Iwe Orin Dafidi 34:9-17

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *