Don’t Offer The Sacrifice Of Fools

Église Saint-Martin de Castelnau-d'Estrétefonds - Le sacrifice d'Abel par Robert Arsène IM31000071

THE SEED “Do not be hasty with your mouth [speaking careless words or vows] or impulsive in thought to bring up a matter before God. For God is in heaven and you are on earth; therefore, let your words be few.” Ecclesiastes 5:1-2 AMP

Fools parade their ignorance in words and actions in the gathering of people. This might be pardoned amongst people, although with its consequences. But in a meeting with our Creator, in His presence, such conduct is regarded as totally unacceptable because God is not a human that you can joke with or say things you don’t mean to. We must be careful of the covenants and promises that our mouths utter in God’s presence, as well as our behaviour. Don’t let emotions rule your mind, but carefully weigh what you want to say before you utter a word, so that you will not experience the painful ordeal of Jephthah, who hastily made an emotional covenant before God and ended up with the sacrifice of his only daughter and child to fulfil his unthoughtful promise after his victory in war. Don’t act carelessly with words like Eli when he said “ He’s God, let Him do what pleases Him” and God did do what pleased Him, but not to Eli’s favour, and the dynasty of the priesthood was taken away from his family. Remember that God is in heaven, and you are on earth; therefore, let your words be few and of reverence before Him.

PRAYER

Lord Jesus, enable me to be wise in words and actions in Your presence always. Amen

BIBLE READINGS: Judges 11:29-35

IRÚGBÌN NÁÀ

“Pa ẹsẹ rẹ mọ́nigbati iwọ ba nlọ si ile Ọlọrun, ki iwọ ki o si mura ati gbọ́jù ati ṣe irubọ aṣiwère: nitoriti nwọn kò rò pe nwọn nṣe ibi. Máṣe fi ẹnu rẹ yara, ki o má si jẹ ki aiya rẹ ki o yara sọ ọ̀rọ niwaju Ọlọrun: nitoriti Ọlọrun mbẹ li ọrun, iwọ si mbẹ li aiye: nitorina jẹ ki ọ̀rọ rẹ ki o mọ̀ni ìwọn.” Oniwasu 5:1-2 BM Awọn alaimoye mā n fi aimọkan wọn hàn ní àwùjọ awọn eniyan ninu ọ̀rọ̀àti ìṣe wọn. Eniyan le f’ojú fo aṣiṣe yí bi o tilẹ jẹ wipe ijiya rè yíò farahàn. Sugbon níwájú Ọlọrun irú ìwà báyìí je ohun ìrírá nitoripe Ọlọrun kī ṣe eniyan ti a le ma ba ṣe àwàdà. A ní látí ṣọra fún àwọn ìlérí tí a bá fi ẹnu wa so níwájú Ọlọrun, bē gẹ̀gẹ̀ní ìwà wà pẹlu. Ma ṣe jẹki idojukọ rẹ se àkóso ọrọ ẹnu rẹ. Sugbon, gbé ọ̀rọ̀rẹ yẹwo ki o to sọ jáde ki o ma bā ní irú ìrírī Jefta ti o fi ìyára ẹnu dá majẹmu níwájú Ọlọrun, eyi ti o ja sí fífi ọmọbirin rẹ́kanṣoṣo ṣe ìrúbo láti san majẹmu naa, tàbí bī Eli tí o ọ̀rọ̀bi alaimoye wipe ‘Ọlọrun ni jékí o ṣe èyí ti o wũ, nitotọ, Olorun si ṣe ohun tí o wũ, sugbon ko já sí ojú rere fún Eli, o gba ipò àlùfáà kúrò ní ìdílé rẹ̀nitori ọ̀rọ̀naa. Rántí wípé Ọlọrun wà lókè ọ̀run, awa sí wá ni aiye, nitorinà ẹ jẹ kí òrò wà mọ niwontunwonsi ati ibọwọ níwájú Ọlọrun.

ÁDÙRÁ

Jesu Olùwà ẹ rán mí lọwọ láti je ọlọgbon nínú ọ̀rọ̀ àti ìṣe mí níwájú rẹ̀. Amin.

BIBELI KIKA: Onídajọ 11:29-35

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *