Faithful God

FAITHFUL GOD
THE SEED
‘’Know therefore that the Lord thy God, He is God, the faithful God, which keepeth
covenant and mercy with them that love Him and keep His commandments to a
thousand generations’’. Deuteronomy 7:9 KJV
We know the God we serve; We know the Lord we worship. The Almighty God answers
our prayers according to His will and plans for our lives and not our decision. But at times in
our ignorance, we resist God’s will because we think we are in control or fear that it might not
work out, forgetting that His way is not our way and it’s beyond finding out.

More so, the faithfulness of God moves beyond our meagre request and His steadfast
love never ceases, His mercies never come to an end, but are new every morning. The fact
remains that God is not a man that He should lie.

He has been faithful in all circumstances surrounding us. He can never lie nor fail,
neither can He deny himself or change. He remains the same forever. He preserves, protects,
guides, blesses, strengthens and heals all our infirmities, even before we ask Him. He knows
what we want. He said “come unto Me all ye that labour and are heavy laden and I will give you rest, for My yoke is easy, and My burden is light.” He’s a faithful God.

PRAYER

Lord, bestow on me the power to uphold your faithfulness and believe it in every circumstance in Jesus Name. Amen
BIBLE READINGS: Deuteronomy 7:6-9

 

OLORUN OLOTITỌ
IRUGBIN NAA
“Nitorinà ki iwọ ki o mọ pé, Olúwa Ọlọrun rẹ, on lí Ọlọrun; Ọlọrun olotọ, tí npá Majẹmu
mọ àti aanu fún àwọn ti o fẹ ẹ, tí nwọn sí pa òfin rẹ mọ́dé ẹgbẹrun iran”. Deuteronomi
7:9
A mọ Ọlọrun ti a nsìn, a sì mọ Ọlọrun tí a nfi ori balẹ fún, Ọlọrun alágbára tí o ngbo
ádùrá wá gẹgẹ bí ìfẹ Rẹ, àti ẹtọ Rẹ fún ayé wá, tí kí í ṣe bí ìpinu wá. Ṣugbọn lọpọ igba ninu
aimọkan wá, a máa nkọ ìfẹ Ọlọrun sílẹ nítorípé a lérò pé a ní agbára lórí ètò Rẹ; tabi a ní ibẹrù
pé kò ní ṣe é ṣe. A ṣí gbàgbé pé ọnà Rẹ kí ṣe ọnà wá, o sí jù ohun tí a lè wadi lọ. Bẹ gẹgẹ òtítọ Ọlọrun kọjaibere wá tí o kéré, àti ìfẹ Rẹ tí o jinlẹ̀ki i dúró. Aanu Rẹ ko dopin ṣugbọn o ndi ọtun lojojumọ. Òtítọ yi, wá sibẹ pé Ọlọrun kí í pa irọ.
O jẹ olotitọ nínú ohun gbogbo tí o yí wá ká. Kò lé pa irọ, kò sí lè ní ijakule. Kò lé se ará Rẹ,
kò sí lè yípadà. O wà títí láíláí. O npá wá mọ, O ndá àbò bó wá, O n tọ ni. O nbukun ní, O n fun ní lókun, O nwo awọn arun wa san. Kí a tó bere lọwọ Rẹ, o mọ ohun ti a fẹ.
“O so wípé è wá sọdọ mí gbogbo ẹni ti o nṣiṣẹ, tí a sì di eru wuwo le lórí, ngo si fun o ní
ìsimi. Àjàgà mi rọrun ẹrù mí sí fuyẹ. Olorun olotito ní.
ÁDÙRÁ
Oluwa fún mi ni agbara lati le dì otito Rẹ mu, kí n sí gbagbọ ni gbogbo ọna ní orúkọ Jésù Àmín
BIBELI KIKA: Johannu 11:38-44

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *