Favorites Versus Intimates

THE SEED
And we know that God causes all things to work together for good to those who love God, to those who are called according to His purpose. Romans 8:28

Yesterday, we discovered that God doesn’t have any preferences. He does, however, cherish connection with His own—God maintained a deep bond with His people throughout the Bible. And as of right now, the family of God now includes everyone who has accepted Jesus Christ as their Savior. Each of the children of the heavenly Father is someone with whom He longs to establish a close relationship. By conversing with Him in His Word and in prayer, we are able to experience this closeness. Intimacy results from a growing friendship that helps us comprehend God, His Word, and His desire for our lives on a deeper level. He begins to shape us into His likeness as we spend time with Him and submit to Him. Then He acts through us, and we serve as a mirror for Him to people in our immediate vicinity (Matthew 5:14-16). Don’t let yourself be content with only being spared from anger. The Lord calls every one of us to step forth in trust and commitment as He longs for us to know Him deeply. He wants us to be like Abraham, who is lovingly referred to as God’s friend (2 Chronicles 20:7).

PRAYER
Lord according to your love let everything work together for my good. Amen.
BIBLE READINGS:  Romans 8:26-30

  ÀÀYÒ TABI Ọ̀RẸ́ TÍMỌ́TÍMỌ́

IRUGBIN NAA
Àwa sì mọ̀ pé ohun gbogbo ni ó ń iẹ́ pọ̀ sí rere fún àwọn tí ó fẹ́ Ọlọ́run, àní fún àwọn ẹni tí a pè gẹ́gẹ́ bí ìpinnu rẹ̀ – Romu 8:28

Ni ọjọ ana, a kọ́ wipe Oluwa kiiṣe ojusaaju. Sibe, Oluwa maa n fẹran ibasepo pelu awon tirẹ, gẹgẹ bi a ti ri ninu ibasepo Re pelu awon kan ninu Bibeli. Nibayii, awon ti o ba ti gba Jesu Kristi ni Olugbala won jẹ ẹbí kan. Gbogbo ọmọ Olorun si ni Oun fe b ani ibasepọ timotimo. Ninu ọ̀rọ̀ Rẹ̀ ati adura, a le ni iriri ibasepo timotimo yii. Ninu biba Oluwa d’ọrẹ ni a le gba sunmọọ. Eyi ti yio mu wa ni oye ti o jinle nipa Olorun ati ife Re. Yi o sọ wa di ara Re nigba ti a ba lo akoko wa pelu Re ti a si jowo aye wa fun. Yio si ma ṣiṣẹ nipasẹ wa, awa yio si da bi awokose Re ni agbegbe wa (Matiu 5:14-16). Kiiṣe ki o sa fun ibinu Re nikan. Oluwa n pe gbogbo eniyan lati sunmọ Oun ninu igbẹkẹle ati ifarajin, ki awa ki o le mọ̀ọ́ si. O fẹ ki a dabi Abrahamu, ẹni ti Oluwa pe ni orẹ Olorun. (2 Kronika 20:7)

ADURA
Oluwa, gẹgẹ bi ifẹ Re, jẹ ki ohun gbogbo ṣiṣẹ pọ̀ si rere fun mi. Amin
BIBELI KIKA: Romu 8:26-30

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *