Fire On The Altar

THE SEED
The fire shall ever be burning upon the altar; it shall never go out. Leviticus 6:13

Those who are spiritually pretentious and those who are spiritually intense are distinguished in the introductory Scripture. That question is best answered by the quantity and intensity of flames on your spiritual altar. As deep reaches out to deep, it searches your existence for its own echo; it cannot be replied by the fire you currently have or the fire you formerly had. We can only be infused with the Holy Fire by patiently approaching the throne of grace. He who waits there patiently and firmly will drink of that Fire and emerge from his contact with God, carrying signs of his travels. You must isolate yourself from the world, that cold world that so quickly takes our Fire, and draw close to the throne of God and the Lamb if you want your soul to be lit with the Fire of God. Close the door after going inside your closet and wait for the Fire there, alone before the throne. When you emerge from it, holy power will surround you, and you will work “in demonstration of the Spirit and of Power,” rather than in your own strength (1 Cor. 2:4). Let’s consider the fire on the altar as a representation of our commitment to the Lord, which results in the best possible use of our gifts. Let’s keep stocking the fire by supplying it with the Bible and persistent prayer. Keep an open mind so the wind of the Holy Spirit can fan the fire into a roaring blaze.

PRAYER
O Lord, let not my usefulness in your presence be extinct, give me the discerning spirit to be renewed for your works. Amen.
BIBLE READINGS:  Leviticus 6

. INA ORI PẸPẸ

IRUGBIN NAA
Ki iná kóò máa jó lórí pẹpẹ naa; ko gbodo ku laeláé. Léfítíkù 6:13

O ni aya lati ran idanwo  nigbati ina ba n jo lori pepe re. Àwọn tí wọ́n jẹ́ ẹlẹ́tàn nínu Emí àti àwọn tí wọ́n jẹ́ alágbára nínu Emí ni a se agbeyewo won nínú ese bibeli ti a ka saaju. A le dahun ibere naa nipa opo ati agbara ina ori pepe re ninu Emi. Bi ibu omi ti n pe ibu omi, oun se awari iwalaaye re fun ogo re. O ko le gbekele agbara ti eniyan ni lowolowo tabi eyi ti o ti ni latehin wa. A le fun wa ni ina Emi Mimọ nipa fifi sũru sunmọ itẹ ore-ọfẹ. Ẹniti o ba fi suuru duro pelu itara ni yoo mu ninu ina lati odo Oluwa, ti yio ni ami ti awọn irin-ajo rẹ. O gbọdọ ya ara rẹ sọtọ kuro ninu aye, ile aye ti o tutu ti o si n pa Ina wa ni kiakia, ki o si sunmọ itẹ Ọlọrun ati Ọdọ-Agutan ti o ba fẹ ki ẹmi rẹ jo pẹlu Ina Ọlọrun. Pa ilẹkun lẹhin ti o wọ inu kọlọfin rẹ ki o duro de Ina nibẹ, iwo nikan niwaju itẹ. Nigbati o ba jade ninu rẹ, agbara mimọ yoo yi ọ ka, iwọ yoo si ṣiṣẹ “ni ifihan ti Ẹmi ati ti Agbara,” ju ninu agbara ti ara rẹ (1 Kor. 2: 4). Ẹ jẹ́ ká wo iná tó wà lórí pẹpẹ gẹ́gẹ́ bí àpẹẹrẹ ìfarajin wa sí Oluwa, èyí tó máa yọrí sí lílo àwọn ẹ̀bùn wa lọ́nà tó dára jù lọ. Ẹ jẹ́ ki ina wa maa jo nípa kika Bíbélì àti gbigba àdúra. Jẹ́ kí ọkàn rẹ̀ ṣí sílẹ̀ ki Ẹ̀mí Mímọ́ lè mu iná Emi re le jo gere.

ADURA
Oluwa, maa jeki ise mi niwaju re ja sa san, fun mi ni emi oye lati di titun fun ise re. Amin.
BIBELI KIKA: Léfítíkù 6

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *