God Is Willing To Heal You

THE SEED
“Then Jesus, moved with compassion, stretched out His hand and touched him, and said to him, “I am willing; be cleansed” Mk. 1: 41 NKJV

God is not only able to heal any sickness or disease, but He is also willing. We have to believe that God’s desire for us is to be in health. For in their minds, many people think God chooses when to heal or not, though this can be true in some situations we are always the determinant of God’s grace in our lives. If the leper had not approached Jesus and asked Him if He was willing to heal him there’s the possibility that he could have died a leper. Even in the case of the Greek woman where Jesus felt that it wasn’t good to feed an alien with the bread meant for the child, her attitude and willingness to receive made her go home rejoicing. Jesus Christ demonstrated to us that He never turned anyone seeking healing away. He didn’t even ask them to become ‘born-again’ first. He only asks that we believe and be willing to receive healing.

PRAYER
Heavenly Father I am thankful that You are not only able, but You are also willing to heal me of any illness that may attack me, in Jesus name Amen.
BIBLE READINGS: Mark 7:25-29

  ỌLORUN SE TAN LATI MU Ọ LARA DA

IRUGBIN NAA
“Nigbana ni Jesu ṣe ãnu, o na ọwo Rẹ̀, o fi ọwo kàn a, o si wi fun u pe, Emi fẹ; di mimo Maaku 1:41 KJV

Ki se wipe Ọlorun ni agbára Lati wo aisan tabi aarun nikan, ṣùgbon o se tan Lati se.A ni lati gbagbọ pe ifẹ Ọlọrun fun wa ni lati wa ni ilera. Nítorí ninu ọkan wọn, ọpọlọpọ awọn eniyan ro pe Ọlọrun yan akoko lati mu larada tabi ko Lati ma se be. Bi o tilẹ jẹ pe eyi le jẹ otitọ ni awọn
ipo kan, awa ni a maa n se okunfa oreofe Ólorun nínú aye wa. Ibase wipe adete naa ko to Jesu lo, ki o si bi I wipe, nje o wuu Lati mu oun larada, o see se ki adete naa ku sinu ete re. Àní nínú ọ̀ràn ti obìnrin Gíríìkì náà níbi tí Jésù ti rò pé kò dára láti bo ajèjì pẹ̀lú ounje ti o to si
omo,íhùwàsi rẹ̀ àti ìmúratan re láti gbà a mú kí ó lọ sí ilé pẹ̀lú ayọ̀. Jesu Kristi fihan wa pe Oun ko le ẹnikẹni ti o n wa iwosan pada rara. Ko tilẹ beere lọwọ wọn lati di ‘atunbi’ ni akọkọ. O Kan beere pe ki a gbàgbo, ki a si setan lati gba iwosan.

ADURA
Baba Orun Mo dupe wipe Iwo nikan lo ni agbára ti o si setan Lati wo mi san ninu aisan eyikeyi ti o le kolu mi, ni orukọ Jesu Amin.
BIBELI KIKA: Máàkù 7:25-29

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *