GOD LOOKS AT THE HEART (PART II)

THE SEED

“This is the stone which was set at nought of you builders, which is become the head of the corner.” – Acts 4:11 (KJV)

Jesus, the cornerstone, was rejected by men because they judged by outward appearance. But God saw His true worth and made Him the foundation of our salvation. People may overlook you because you don’t fit their idea of “perfect,” but God’s vision is greater than human opinion.

God chooses and elevates those who walk in His purpose, regardless of how others perceive them. Embrace who God says you are, not what people say. Your worth is defined by God’s plan, not man’s rejection.

BIBLE READINGS:  1 Peter 2:4–10 (KJV)

PRAYER: Father, help me to embrace who You say I am. Let my confidence rest in Your purpose and not in people’s opinions, in Jesus’ name. Amen.

OLORUN NWO OKAN (APA KEJI)

IRUGBIN NAA

Eyi li okuta ti a ti ọwọ́ ẹnyin ọmọle kọ̀ silẹ, ti o si di pàtaki igun ile. Ise awon Aposteli 4:11

Jesu, ti o je Pataki Igun ile, awon eniyan koo sile toriwipe won se idajo re nipa bi o se ri lati ita. Olorun ri iwon re , O si fi se ipinle igbala wa. Awon eniyan le fi oju pa o re nitoripe oo jo eni ti o pe niwaju won, sugbon iran Olorun ju imo eda lo. Olorun ma nyan awon ti won rin ninu eto re, O si ma ngbe won ga, ko nii fi se bi awon gbogbo eniyan se nri won. Diro mo oun ti Olorun so wipe o je, kiise oun ti awon eniyan so. Eto Olorun ni o nfi iwon re han, kiise ikosile eniyan.

BIBELI KIKA: 1 Peteru 2:4-10

ADURA: Baba, ranmi lowo lati diro mo oun ti o so wipe mo je. je ki igbekele mi sinmi ninu eto re, kiise ninu ero awon eniyan. Ni Oruko Jesu. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *