God, My Anchor

 

GOD, MY ANCHOR 

THE SEED 

“Which hope we have as an anchor of the soul, both Sure and steadfast, and which enter  into that within the veil.” Hebrews 6:19 

Depression renders one unfit or unable to receive inner peace. Discouragement  magnifies the burden and renders it too heavy to bear. Distress is the outcome of a heart that  has no anchor on the LORD. Anchored to Christ, at this time that many terrors are coming upon  the world, is the best safety mode. Men’s hearts will fail unless our hearts are anchored to His  voice of love. God is the anchor of the heart of the soul of the one with Christ.  

How terrible it feels when you feel alone in this world, which can literally mean an  anchorless ship being in danger of sinking below a troubled sea. Satan seeks to wreck the soul  of the one who is not securely anchored to Christ; but the soul that is anchored to Christ is  indeed safe and steadfast.  

So, we must lay hold on that hope set before us, for our hope is secure in him. God is  our anchor, not only for eternity, He is your strong, safe and secure anchor right now. Our  eternal salvation is immovably secured and anchored in Christ alone. In this life, we are to lay  hold of Christ, who is the anchor of our soul, if we are to be rewarded as a good and faithful  servant. 

PRAYER 

Lord, help me to make you my anchor and never go astray from you now and ever. Amen  BIBLE READINGS: Hebrews 6:16-19 

OLORUN, IDAKORO MI 

IRUGBIN NAA 

“Eyiti awa ni bi idakoro okan, ireti ti o daju ti o si duro sinsin, ti o si wo inu ile lo leyin aso  ikele.” Heberu 6:19 

Irewesi okan a maa soni di alaare tabi ki o le ifokan bale jina sini. 

Irewesi a maa bukun ajaga, yio si mu ki o wuwo lati ru. Iponju lo maa n gbeyin okan ti ko bani  idakoro. Ki idakoro wa ki o wa ninu Kristi ni abo ti o peye ni akoko ti eru gba aye kan yii. Okan  eniyan yoo jaa kule ayafi bi a gbe okan wa le ohun ife re. Olorun ni idakoro okan ati emi awon ti  o wa ninu Kristi. 

O je ohun ti o buru gidigidi, nigbati o ba da bii pe o nikan wa ninu aye, eyiti o tumosi oko  oju omi ti ko ni idakoro, ti o wa ninu ewu iteri. 

Satani n lepa lati pa okan ti ko ni idakoro ninu Kristi run, sugbon okan ti o ni idakoro ninu Kristi  ni a o gbala ti yio si duro sinsin 

Nitorinaa, a gbodo di ireti eyiti a gbe ka iwaju wa mu. Nitoriti ireti wa daju ninu re.  Olorun ni idakoro wa, kii se fun ayeraye nikan, ohun ni idakoro re ti o lagbara, ti odaju, ti o si  duro sinsin. 

Igbala ayeraye wa, eyi ti ko le ye nbe ninu Kristi nikan. Ninu aye yii, a ni lati di Kristi mu,  eniti se idakoro emi wa, ti a ba fe lati gba ere gege bii omo odo rere.  

ADURA 

Oluwa, ran mi lowo lati le fi o se idakoro mi, ki n ma se sako kuro lodo re nisisiyi ati titi lae. Amin

BIBELI KIKA: Heberu 6:16-19 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *