GOD OF ALL SEASONS
THE SEED
“Who delivered us from so great a death, and doth deliver: in whom we trust that he will yet deliver us.” — 2 Corinthians 1:10 (KJV)
God’s faithfulness covers our past, sustains our present, and secures our future. He is the same God who delivered you before, working even now and ready to deliver again tomorrow. His track record of mercy should fuel our trust in His continued faithfulness. We must learn to reflect and remember what God has done for us. Those testimonies are not meant to be forgotten; they are faith-builders for the seasons ahead. If He did it before, He can do it again. This truth anchors our hearts when new trials come. Beloved, do not allow the uncertainties of today or the worries of tomorrow to overshadow the faithfulness of God in your heart. Your seasons may change, but your God remains constant and dependable.
Reflection: The God who helped you before will help you again.
BIBLE READING: 2 Corinthians 1:8–10
PRAYER: Father, thank You for being faithful in every season of my life—past, present, and future. Amen.
OLORUN GBOGBO AKOKO
IRUGBIN NAA:
“Ẹni tí ó gbà wá kúrò nínú irú ikú tí ó tóbi bẹ́ẹ̀, yóò sí tún gbà wá; òun ní àwa gbẹ́kẹ̀lé pé yóò sí máa gbà wá síbẹ̀síbẹ̀,..” II Korinti 1:10
Otito Olorun n bo àná wa, O nse itoju oni wa, O si nse ipese ojo ola wa. Òhun ni Olorun kan naa to gba o nigba kan ri, O nsise re lowolowo, O si setan lati gba o lojo ola. O yẹ ki ise aanu Re tubo je ki a gbekele otito Re si. A gbodo ko lati ronu ati ki a si ranti ohun ti Olorun ti se fun wa. Awon eri yi ni ko ye ki a gbagbe; o je ohun ti nmu igbagbo dagba fun akoko ti nbo ni iwaju. Ti Olorun ba se nigba kan ri o tun le se lekan si. Otito yii ngbe okan wa ro nigba ti idanwo ba de. Ayanfe, ma se je ki aidaniloju oni tabi aniyan ola bori otito Olorun ninu okan re. Akoko re le yipada, sugbon Olorun re ko yipada, o si le gbekele.
Asaro: Olorun to ti ran o lowo tele, yoo tun ran o lowo sii.
BIBELI KIKA II Korinti 1:8-10
ADURA: Baba, O se wipe o je olotito ninu gbogbo akoko aye mi; ana, oni ati ojo iwaju. Amin.