Goodness Of God

THE SEED

“Who satisfieth thy mouth with good things; so that thy youth is renewed like the eagle’s.” Psalms 103:5
The Bible offers two definitions of God’s goodness. One relates to His personality, while the other concentrates on His deeds. When God is praised in Psalm 119:68, it is said, “You are good, and You do what is good.” The focus of the first part of that passage is on God’s inherent goodness. He is “morally great, incredibly gorgeous, intensely joyful, and extravagantly abundant,” in other words. However, since we are discussing God, the kindness attributed to Him is elevated to the highest degrees. Since Elohim is good and His nature is inherently good, He can only bestow upon His offspring only good things. The first verse makes it quite obvious that God loves to bless His people. He provides us with wholesome food to fulfil our appetites so that we can regain our youth like an eagle. As we proclaim His Word over our lives, families, homes, businesses, jobs, communities, and countries, He makes sure that it actually happens so that we can give Him the praise that is His due. He also gives us His Word to fulfil our lips. He demands that we submit to His authority, His commands, and the laws of the country in which we reside. God supports you. He is on your side. He is there, preparing a scheme to help you. You are the focus of His devotion, and since He is divine, everything He says and does is motivated by an enormous, overwhelming, and divinely generous kindness toward you.

PRAYER

May I continue to bask in the goodness of God throughout the days of my life.

BIBLE READINGS: Psalms 103

IRE OLUWA

IRUGBIN NAA

Ẹni tí ó fi ohun dídára tẹ́ ọ lọ́rùn kí ìgbà èwe rẹ̀ lè di ọ̀tún bí ti ẹyẹ idì. Psalmu 103:5

Bibeli funni ni itumọ meji tí oore Ọlọrun jẹ. Ọkan túmọ sí ohun tí Ọlọrun jẹ, nígbà tí omiran sọ nípa ìṣe Rẹ. Nigbati a yín Ọlọrun ninu Orin Dafidi 119:68 a sọ pe, “Ẹni rere ni iwọ, iwọ sì nṣe ohun rere.” Ohun tí apá kán, àkọ́kọ́, nínú ọ̀rọ̀ àyọkà, dá lé lórí ni oore tí Ọlọ́run dá sílẹ̀. Ó jẹ́ “ẹni títóbi ní ti ìwà híhù, ẹlẹ́wà púpọ aláyọ̀ púpọ̀, O sì jẹ́ ọlọrọ lọ̀pọ̀ yanturu. Niwọn igbati o jẹ pé a nsọ ọrọ nipa Ọlọrun, inurere ti o ni, ni a gbé ga dé ibí ayé nla. Niwọn igbati Elohim, orúkọ tí a tún fi npé Ọlọrun jẹ èyí tí o dára, ìwà Rẹ sí dára ohun tí o dára nípa Rẹ nikan ni o le fún àwọn ọmọ Rẹ. Ẹsẹ bíbélì akọkọ fi hàn gbangba pé Ọlọ́run fẹràn lati máà bukun àwọn ènìyàn tirẹ. O n pèsè oúnjẹ fún wa lọpọlọpọ lati fi tẹ wá l’ọrùn ki ìgbà èwe wá lè dàbí tí ìdí. Bí a ti ṣe n polongo ọrọ Rẹ lori ayé wá, lori ẹbi, ile, òwò, iṣẹ, agbègbè ati orilẹ-ede wà; O sì rí mọ pé a lè fún Òun ní ìyín logo tí o tọ fún ùn. O nfuń wà ní ọrọ Rẹ lati kún ẹnu wà. O fẹ kí a tẹriba fun aṣẹ Rẹ, ofin Rẹ, ati awọn ofin orilẹ-ede ti a ngbe. Ọlọrun n tí ọ lẹhin, O wà ní ẹgbẹ́ ọdọ rẹ, O wà ní ibí, O n pèsè ohun tí yíò fi ran ọ lọwọ. Iwọ ní o jẹ ohun ti ọkan Rẹ dojukọ, nitori o jẹ ẹni at’oke wa, ohun gbogbo ti O bá n sọ, ti O sí n ṣe ní o jẹ ọpọlọpọ ai le fẹnu sọ àti inurere Rẹ sí ọ.

ADURA

Oluwa kì èmi le máà gbé ninu ojurere Rẹ. Amin.
BIBELI KIKA: Psalmu 103

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *