Grace For Accountability

THE SEED
“For it is written As I live, says the Lord, every knee shall bow to Me and every tongue shall confess to God. So then each of us shall give an account of himself to God.”Romans 14:11-12

To be spiritually responsible is to be acceptable to God and that is our greatest duty. When we can stand with what life throws at us it means we are responsible. One of the things that make us responsible is our character. Without responsibility, one can’t be fruitful. We need to be responsible Christians because God is watching us, according to the gospel of John 15:16, “you didn’t choose me but I chose you and appointed you that you should go and bear fruit and that your fruit should remain,” that is responsible. In life, we should have that at the back of our minds. We should also know that we have responsibilities to people that God connect with us to also bear good fruit. God rewards us when we obey His call for duty. You may ask, How else can I be responsible? Be in control of your action and reaction to things, look after others in your care And be obedient in carrying out your duties no matter the situation.

PRAYER
Father help me not to fail in my duty.
BIBLE READINGS:  John 15:1-8

   OORE-OFE FUN ISIRO

IRUGBIN NAA
“Nitori a ti kọ ọ bi mo ti wà laaye, ni Oluwa wi, gbogbo ẽkun ni yoo kunlẹ fun mi ati gbogbo ahọn yoo jẹwọ fun Ọlọrun. Nítorí náà, olúkúlùkù wa ni yóò jíhìn ara rẹ̀ fún Ọlorun.”— Róòmù 14:11-12

Wiwulo nínú emi ni oun to se itewogba SI Ólorun, eyi ti n se ojuse wa ti o ga julo.  Ti a ba le duro sinsin Lati koju oun ti o doju ko wa, ígba yen lato je ẹniti o wulo. Ikan nínú oun ti o mu wa wulo ni iwà wa. Laisi ojuse, ènìyàn ko le so eso.A gbodọ̀ je kristẹni ti o wulo nítorí pé Ọlorun ń wo wa, gege bí ìhìn rere ti Jòhánù 15:16 ṣe sọ, “Ẹ̀yin kò yàn mí, ṣùgbon èmi ni mo yàn yín, mo sì yàn yín pé kí ẹ lọ, kí ẹ sì so èso, kí èso yín sì máa wà, eyi ni a n pe ni iwulo.Ni igbesi aye, o yẹ ki a fi eleyi sokan. A tún gbodọ̀ mọ̀ pé a ní àwọn ojúṣe sí àwọn ènìyàn tí Ọlorun so mo wa láti so èso rere pẹ̀lú. Ọlọrun san esan fun wa nigba ti a ba pe wa si ise re, ti a si gbọràn. O le beere wipe, bawo ni mo se le je ẹniti o wulo? Je adari iṣe ati íhùwàsi re, tọju awọn ti o wa ni Abe re, Ki o si gbọràn bi o se n se awọn ojuṣẹ rẹ bi o ti wu ki o ri.

ADURA
Baba ran mi lowo lati ma kuna ninu ise mi.
BIBELI KIKA: Jòhánù 15:1-8

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *