GUARDING YOUR HEART

THE SEED
“Above all else, guard your heart, for everything you do flows from it.” Proverbs 4:23 (NIV)

The heart is the wellspring of life. It is the centre of our thoughts, desires, and actions. This is why Scripture warns us to guard it carefully, protecting it from the distractions, temptations, and influences
that can lead us away from God’s purpose. Guarding our hearts means being mindful of what we allow into our minds and spirits. It means filtering out negativity, resisting bitterness, and choosing thoughts that align with God’s truth. Just as a fortified city stands strong against attack, a guarded heart remains steadfast in faith, unshaken by the
storms of life. As we go about our day, let’s keep our hearts centred on Christ, for from it flows the direction of our life.

BIBLE READING: Proverbs 4:20-27
PRAYER: Lord, help me to guard my heart always.
Protect my thoughts, guide my words, and let my
actions reflect Your truth in Jesus’ name, Amen.

DI DÁÀBÒ BO ỌKÀN RẸ IRUGBIN NAA
“Jù gbogbo ohun ìpamọ́, pa àyà rẹ mọ; Nítorípe láti inú rẹ̀ wa ní orísun ìyè.” Òwe 4:23

Ọkàn ni orisun iye. O wa ni aarin awọn ero wa, ohun ti ọkàn wa nfẹ, ati awọn iṣe wa. Ìdí nìyí tí Ìwé Mímọ́ fi kìlọ̀ fún wa láti ṣọ́ ọ dáradára, kí a sì dáàbò bò kuró lọ́wọ́ Ìdánwò àti àwọn ètekéte ti o lé dárí wa kuro nínú ero Ọlọ́run fun wa. Ṣí ṣọ́ ọkàn wa túmọ̀
sí iṣọ́ra fún ohun tí a ńjẹ́ kí ó wọ inú ọkàn wa àti ẹ̀mí wa. Èyí jẹ́ gbí- gbọn èrò òdì dànù, kí a kọ ìkorò ọkàn, yíyan àwọn ìrònú tí ó bá òtítọ́ Ọlọ́run mu.
Gẹ́gẹ́ bí ìlú olódi ṣe dúró gbọn-in lòdì sí ìkọlù, bẹ́ẹ̀ náà ni ọkàn ti a nṣọ́, le dúró ṣinṣin nínú ìgbàgbọ́, ti a ko lé e mì, nípa àwọn ìjì ayé. Bi a ti nlọ nipa ọjọ wa, ẹ jẹki a pa ọkan wa pọ̀ sọ́dọ̀ Kristi, nitori lati ọdọ Rẹ ni itọsọna igbesi aye wa ti nṣàn wa.

BIBELI KIKA: Òwe 4:20-27
ADURA: Oluwa ran mí lọ́wọ́ láti ṣọ́ ọkàn mi nigbagbogbo. Pa èrò inú mí mọ, ṣọ́ ọ̀rọ̀ ẹnu mí, jẹ́kí ìṣe mi fi òtítọ́ Rẹ hàn ni orúkọ Jésù Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *