Guilt And Grace

THE SEED
“I said, “I will confess my transgressions to the LORD.” And you forgave the guilt of my sin.” Psalms 32:5

David spoke to that reality in Psalm 32. He had made a total mess of his life. His moral failures included adultery and murder. David acknowledged that when we mess up, we are eaten up inside if we keep quiet. Like the women who brought their statutes to the temple, David had an inner urge to confess his sin. David confessed his sin to the Lord. Yes, there were people in his life with whom David needed to come clean. But only God could grant the full pardon his soul craved. When we mess up, our guilt is first of all toward our Creator, whose law we have violated. How do you find real forgiveness? Not by way of an offering sacrifice at any temple. Confess to God—and he will forgive the guilt of your sin.

BIBLE READING: PSALM 32

PRAYER: Lord, we can’t cover our sins, but by the blood of Christ you can. Bless us with the grace of your forgiveness and wash us clean. Amen.

ÌDÁLEBI ATI OORE-OFE

IRUGBIN NAA
“Mo sọ pe, Emi o jẹwọ irekọja mi fun OLUWA. Iwo si ti dari ese mi ji.” Orin Dafidi 32:5

Dáfídì sọ òtíto naa nínú Iwe Orin Dafidi 32. Ó ti ba ìgbésí ayé rẹ̀ je pátápátá. Lára àsise rẹ̀ ni panṣágà àti ìpànìyàn. Dafidi mo wipe nigba ti a ba se àsise ti a ko si jewo re, yio ma je ipalara fun wa. Gege bí àwọn obìnrin tí won mú àwọn ìlànà àgbékalẹ̀ wọn wá sí tempìlì, Dáfídì ní imolara láti jewo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀. Dafidi jẹwọ ẹṣẹ rẹ fun Oluwa. Beẹ̀ ni, àwọn èèyàn kan wà nínú ìgbésí ayé rẹ̀ tí Dáfídì nílò láti jewo Ara re fun. Ṣugbọn Ọlọrun nikan ni o le funni ni idariji ni kikun ti ọkàn rẹ nfẹ. Nigba ti a ba se àsise, ìdálebi Okan wa maa n lo sodo eledà a wa, ẹni tá a ti rú òfin rẹ̀. Bawo ni o ṣe le ri idariji otito gba? Kì í ṣe nípa ìrúbọ Lori pepe. Jẹwọ fun Ọlọrun,yoo si dari ẹṣẹ rẹ jì o .

BIBELI KIKA: Iwe Orin Dafidi 32

ADURA: Oluwa, a ko le bo ese wa, sugbon nipa eje Kristi o le Fi oore-ọfẹ idariji rẹ bukun wa ki o si wẹ wa mọ. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *