THE SEED
“If only my master would see the prophet who is in Samaria!”2 Kings 5:3
Naaman was a great general with a terrible problem: leprosy. Though he moved in powerful circles, no one could offer any hope for his condition—except a young slave girl from Israel who understood God’s power and was willing to share where true hope was found. This slave girl shared the good news of God with a leader who was tempted to think he could handle life on his own. Naaman needed to learn from others. What will it take for us to learn from unexpected sources? It will take a spirit of humility. Naaman’s humility almost ran dry when Elisha told him to bathe in the Jordan! Sacrifice your pride. Today God may wish to teach you a lesson of faith. Be open to being taught from a source you don’t expect.
BIBLE READING: 2 KINGS 5:1-14
PRAYER: Lord, we often think we know it all. But you intend new faith lessons for us. Open our eyes. Amen.
GBIGBO ỌLORUN NI IBI IYANU
IRUGBIN NAA
“ Ti oga mi ba le ri woli ti o wà ni Samaria!” 2 Awọn Ọba 5:3
Naamani jẹ olori Ogun kan pẹlu iṣoro nla ti o je ẹtẹ. Bi o tile je pe ipo nla ni o wa, ko si enikan ti o le ran n lowo nínú isoro re yàto si omo erubinrin kekere ti o wa Lati Israeli eniti o ni oye agbara Ọlorun ti o si n Fe Lati Fi agbara Ọlorun naa han nibiti ireti tòóto wa. Omọbìnrin yìí sọ ìhìn rere Ọlorun fún aṣáaju kan tó wù ú ti o ro wipe oun le da isoro aue ohun yanju. Naamaani nilo Lati ko eko lodo ẹlòmíran. Kí ni yóò na wa láti kekọ̀o láti orísun àìròtelẹ̀? Eyi yoo gba ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀. Ìrẹ̀lẹ̀ Náámánì ti fe e dopin nígbà tí Èlíṣà sọ fún un pé kó lọ wẹ̀ nínú Jodánì! Re ara re síle. Loni Ọlọrun le fẹ lati kọ ọ ni ẹkọ igbagbọ. Se tan lati kọ ẹkọ lati orisun ti o ko nireti.
BIBELI KIKA: 2 Àwọn Ọba 5:1-14
ADURA: Oluwa, a ro pe a mọ ohun gbogbo tan, Ṣugbọn o pinnu awọn ẹkọ igbagbọ tuntun fun wa. La oju wa. Amin.