Who Are The Missionaries?

THE SEED
If I say, “I will not … speak anymore in his name,” his word is in my heart like a fire …” Jeremiah 20:9

Today Brazil sends more missionaries to serve on international fields than Great Britain or Canada. The small nation of South Korea is already sending half as many missionaries into the world as is the United States, and the number is growing. These missionaries are serving all over the globe—including more than 35,000 in North America! But today Christians from around the world are being caught up into the delight of fulfilling Jesus’ great commission (Matthew 28:19-20). Jeremiah explains why that is so. The gospel has within it energy birthed by the Spirit that compels us to tell others. Jeremiah declares that he cannot stop speaking the word of the Lord. Suppressing the gospel witness by failing to speak will only create in his heart a fire that will consume him. He is right, of course. Sometimes we are so intimidated by an opportunity to share the gospel that we think the easy way out is to say nothing. But there is emotional cost to not speaking the gospel. If we do not seek to set the world ablaze with the fire of God’s truth and love, we will feel the heat of our own guilt and failure to obey our Lord’s commission.

BIBLE READING: JEREMIAH 20:7-13

PRAYER: Lord, let the missionary zeal of Christians everywhere inspire our own witness. Help us to share your good news. Amen.

TANI AWON AJINRERE

IRUGBIN NAA
“Ti Mo ba sọ, “Emi kii yoo…sọrọ mọ ni orukọ rẹ,” ọrọ rẹ wa ninu ọkan mi bi ina…” Jeremiah 20: 9

Loni, orile ede Brazil ran awọn ajihinrere jade ju orile ede Gẹẹsi tabi Ilu Kanada. Orilẹ-ede kekere ti South Korea ti n ran ajinrere si agbaye eyi ti o to idaji iye ti orile ede Amẹrika ti ran jade, won si n ran awon ajinrere jade si i. Awọn ajihinrere wọnyi n ṣiṣẹ ni gbogbo agbaye — pẹlu diẹ sii ju egberun marundinlogooji ni Ariwa America! Ṣugbọn loni awọn onígbàgbo ni gbogbo agbaye ni won n Fi idunnu Lati mu Ileri Jesu se (Matteu 28: 19-20). Jeremiah salaye idi ti iyẹn fi ri bẹ. Ihinrere ni Agbara Lati kan n nipa fun wa pe, ki a polongo ihinrere fun awọn miiran. Jeremiah ṣalaye pe ohun ko le sai sorọ Ọlorun. Didekun Jeremiya Lati maa polongo ihinrere yio túmo mu ki Ina re ma a Jo fun Oluwa si. Beeni, òóto lo so. Nigba miiran, a maa n berù Lati polongo ihinrere Debi wipe, a lero wipe ki a dake ni o to ṣùgbon o maa n ni ipalara Lori aye wa ti a ko ba polongo ihinrere. Ṣugbọn idiyele ẹdun wa lat. Ti a ko ba wa bi a o se tona imole ihinrere Ọlorun nípase otito atí ife, a o ni ìdálebi lokan wa wipe a Kuna Lati gboran si ase Ọlorun.

BIBELI KIKA: JEREMIAH 20: 7

ADURA: Oluwa, jẹ ki itara ihinrere ti awọn kristeni nibi gbogbo ṣe iwuri fun ẹri tiwa. Ran wa lọwọ lati polongo ihinrere rẹ. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *