THE SEED
“Oh, give thanks to the Lord, for He is good! For His mercy endures forever.” — Psalm 136:1 NKJV
Times and seasons change, but God’s mercy remains constant. His love, truth, and Word endure forever. The pandemic of 2020 was temporary, but God’s faithfulness stood firm. God’s mercy is not seasonal; it is everlasting. When everything around us feels uncertain, His mercy gives us strength to keep standing. It is this same mercy that forgives, restores, and preserves us daily. What a great assurance that His mercy never runs dry! As the world shifts and uncertainties arise, hold fast to God’s unchanging nature. His mercy is your anchor through all seasons.
BIBLEREADINGS: Psalm136:1–9
PRAYER: Lord, renew my hope daily in Your unfailing love and mercy. Amen.
AANU RE DURO TITI LAE
IRUGBIN NAA
Ẹ fi ọpẹ fun Oluwa: nitoriti o ṣeun; nitori ti aanu rẹ̀ duro lailai. Psalm 136:1
Igba àti akoko maa n yipada sugbon aanu Olorun duro titi lae. Ife Re, otito àti Oro Re duro laelae. Ajakale arun COVID ti odun 2020 wa fún igba kan sugbon ododo Olórun duro deede. Aanu Olorun kò duro lori igba tabi akoko, o wa titi laelae. Ni igba ti ohun gbogbo ni ayika wa ba daru, aanu Re ni o n fún wa ni agbára lati le duro deede. Aanu yi kan naani o n dariji,ti o nmu wa pada bosi po ti o si n da wa si lojoojumo. Bi aye tin sún ti idaru dapo n gbile sii, di Olorun ti kii ye mu sinsin. Aanu Re ni ole rọmọni gbogbo igba àti akoko.
BIBELI KIKA: Psalm 136:1-9
ADURA: Oluwa, so ̣ ireti mi d’otun lojojuumo ninu ife ailopin àti aanu Re. Amin.