HIS WORD OUTLASTS EVERY SEASON

HIS WORD OUTLASTS EVERY SEASON

THE SEED

“The grass withers, the flower fades: but the word of our God shall stand for ever.” — Isaiah 40:8 (KJV)

Everything changes trends, seasons, and circumstances—but God’s Word remains. By His Word He created, by His Word He upholds, and by His Word He still brings life where death has settled and hope where despair has lingered. Testimonies confirm it: God’s Word spoken in faith breaks chains, restores health, rebuilds homes, and renews minds. When you agree with Scripture, you align with what cannot fail. Heaven and earth may pass away, but His Word endures. Read it. Believe it. Declare it. The eternal Word will do eternal work in you.

Reflection: God’s Word is not fragile; it is final.

BIBLE READING: John 1:1–5

PRAYER: Lord, plant Your unchanging Word deep in me. Help me believe and declare it until it bears fruit. Amen.

 

ORO RE WA TITI NI GBOGBO AKOKO

IRUGBIN NAA:

Koriko nrọ, ìtànná nrẹ̀: ṣugbọn ọ̀rọ Ọlọrun wa yio duro lailai. Isaiah 40:8

Ohun gbogbo nyipada – isele ode oni, akoko ati gbogbo isele ayika. Sugbon Oro Olorun duro. Nipa Oro Re, O seda, nipa Oro Re, O gbeniro, ati nipa Oro Re O mu iye wa si ibiti iku ti joba, ati ireti nibiti ko si ireti mo. Awon eri ti a ngbo nfi idi re mule: Oro Olorun ti a so nipa igbagbo maa nja ajaga, o nda alafia pada, o ntu ile se, o si nso okan dotun. Bi o ba gba Iwe Mimo gbo, a ntele ohun ti ko le kunna. Orun ati aye le koja lo, sugbon Oro Re wa titi laelae. Ka Bibeli, gbaa gbo, so oro re jade. Oro ayeraye na yoo se ise ayeraye ninu re.

ORO: Oro Olorun kii se ohun yepere, ase ni.

BIBELI KIKA Johannu 1:1-5

ADURA: Oluwa, gbin Oro Re ti kii yipada jinle ninu mi. Ranmilowo lati gbagbo kin si maa so titi yio fi so eso. Amin

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *