I Will Extol Thee Oh Lord

THE SEED
“I will Extol thee, O LORD; for thou has lifted me up, and hast not made my foes to rejoice over me.” Psalm 30:1

If the hair on our head were tongues, they aren’t enough to give thanks unto the Name of the Lord for all His Wonderful works in our lives! So numerous, we can’t start counting them one after the other. Even if we have ten thousand tongues they won’t still be enough! Let all our hearts rejoice in praising Him all the time, for Him alone that is doing wonders. Blessed be the Name of our God for the breath of life each day, Blessed be His Name for sleeping and waking up well, hale and hearty, Blessed be our God that preserved our going out and our coming in safely, Blessed be the Lord of Host that didn’t allow the plan and pranks of our enemies to come to pass in our lives. Blessed be the Name of our great Provider, Blessed be our great Healer, healing us when we are ill (Spiritually and Physically). He’s indeed worthy of our Thanksgiving for being our all in all and our Solid Rock that upholds us. For Him alone that will see us through to the end of our days on Earth. Thank you Jesus, we are so grateful. Amen! Glory!! Hallelujah!!!

BIBLE READING: Psalm 136:1-10

PRAYER: Oh Lord God, make my mouth always full of Your Thanksgiving in Jesus Name. Amen.

EMI YIO GBE O GA OLUWA

IRUGBIN NAA
Emi o gbe ọ ga, Oluwa; nitoriti iwọ ti gbé mi soke, iwọ kò si mu ki awọn ọta mi ki o yomi.Orin Dafidi 30:1

Bí irun orí wa bá je ahon, wọn kò tó láti yin oruko Olúwa fún gbogbo iṣe ìyanu Re nínú ayé wa! Ore na Po to be ge, a ko le maa ka won ni konkon. Ti a ba tile ni ẹgbẹrun mewa ahọn wọn ko to! Jẹ ki gbogbo ọkan wa yọ lati maa yin n ni gbogbo igba, nitori oun nikan ti o nṣe ise iyanu.Olubukun ni fun Oruko Olorun wa fun emi iye lojoojumo, Olubukun ni fun Oruko Re fun sisun atí Jiji láyo nínú ilera pipe. Olubukun ni fun Olorun wa ti o pa ijade wa ati iwole wa mo. Olubukun ni Oluwa to ko gba ero atí arekereke Ota Lati wa SI imuse. Olubukun ni fun Oruko Olupese wa nla, Olubukun ni Oluwosan nla wa, ti n wo wa San ti a ba ni ailera(nipa ti emi atí ara). Nitootọ O yẹ ki a maa Fi ope fun nitori o je oun gbogbo fun wa ati Apata nla ti o gbe wa duro. Fun Oun nikan ti yoo wa pelú wa titi ọjọ aye wa lori ile aye. O ṣeun Jesu, a dupẹ pupọ. Amin! Ogo!! Halleluyah!!!

BIBELI KIKA: Iwe Orin Dafidi 136:1-10

ADURA: Oluwa Ọlọrun, jẹ ki ẹnu mi kun fun Ọpẹ Rẹ nigbagbogbo ni Orukọ Jesu. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *