Infinite Grace That Exist In God’s Word

THE SEED
“For the word of God is living and powerful, and sharper than any two-edged sword, piercing even to the division of soul and spirit, and of joints and marrow, and is a discerner of the thoughts and intents of the heart.” Hebrew 4:12

The Expression (WORD) of God is such a strong weapon that, when stood up clearly, it makes evil spirits quickly get away. Assuming you are searching for triumph in any aspect of your life, I urge you to begin reciting the Book of scriptures without holding back. Read the promises of God, accept that He can and will convey you in your difficult situation. No mountain is so high and no valley is profound to the point that the hand of God can’t reach down and grab you out of danger! The Holy Book is God’s diagram for our lives. You can have what this book says you can have. You can do what it says you can do. You have no restrictions as an offspring of God. Anything you are searching for to fill that vast opening in your life, offspring of God, pray and request that He carry it to pass. Call upon Jesus and you will have anything you ask in His name. That’s what His WORD guarantees. We can accomplish the impossible when we are holding God’s hand and He is strolling us down the way toward our heavenly fate. With Him, nothing is impossible!

PRAYER
My father and my God I come before you at this moment, create in me the heart that will accommodate Your word for greater purpose in Jesus Name.
BIBLE READINGS: Matthew 4: 1-4

OORE OFE AILOPIN TI MBE NINU ORO OLORUN

IRUGBIN NAA
“Nitori oro Olorun ye, o si li agbara, o si mu ju idakida oloju meji lo, o si n gunni ani titi de pipin okan ati emi niya, ati orike ati ora inu egungun, on si ni olumo ero inu ati ete okan.” Heberu 4: 12

Oro Olorun je ohun ija ti o lagbara, nigba ti a ba muu lo daradara, a maa mu ki emi esu sa kiakia, ti o ba n wa aluyo ni ona kan tabi ekeji laye re, mo ro o ki o bere si ni ka iwe mimo ni akosori lai bojuweyin. Ka nipa awon ileri Olorun, gbagbo wipe o le gba o, yio si gba o ninu isoro re. ko si oke ti o ga tabi petele ti o jin, ti owo Olorun ko to, lati fa o yo jade kuro ninu ewu. Iwe mimo je aworan Olorun fun aye wa. Iwo yio ni ohun gbogbo ti iwe yii ba so wipe iwo yio ni, o si le se ohun ti iwe yii ba so wipe o le se. gege bi omo Olorun, ko si gbendeke fun o. ohunkohun ti o ba se alaini, omo Olorun, gba adura pe ki o muu wa si imuse. Kepe Jesu, iwo yio si ri ohunkohun ti o ba bere ni oruko re gba. Eyi ni idaniloju ti oro re fun wa. Ohun gbogbo ti o dabi wipe ki yio see se, yio di sise fun wa niwon igba ti a ba di owo Olorun mu ti o si nba wa lo lona naa ti o toka sorun. Pelu Olorun, ohun gbogbo ni sise.

ADURA
Baba mi ati Olorun mi, mo wa si iwaju re ni akoko yii, da okan ti yio faye gba oro re fun anfani nla si inu mi. Amin.
BIBELI KIKA: Matteu 4: 1-4

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *