Inhale Confidence And Exhale Self-Doubt

THE SEED

“Let us hold fast the confession of our hope without wavering, for He who promised is faithful.” Hebrews 10:23 NKJV

The above Scripture teaches us two important things that will make us successful children of God. Firstly, it admonishes us to hold fast to the confession of our faith, our faith in God, and our belief that He will never fail us if don’t fail ourselves. The confession of our faith feeds our confidence to become stronger. When our confidence in the Lord is strong, then we can walk the aisle of faith to tap into the supernatural and claim our blessings, to say boldly that “God is within us, we shall not be moved; God shall help us, just at the break of dawn.”
Secondly, this same Scripture warns us again about harbouring doubt. It says we should confess our faith without “wavering”. To waver is to doubt. Don’t doubt yourself to fit into the
blessing God has promised you. Treasure who God has made you and walk with Him diligently. Remove your focus from your inadequacy because it is not an obstacle to God’s promise but an instrument for the enemy to make you reject the goodness of God. Never doubt God, He will surely bring His word to fulfilment in our lives.

PRAYER

Father in Jesus’ name, I exhale every spirit of self-doubt and inhale divine confidence to receive my blessing. Amen

BIBLE READINGS: Psalm 46:1-5

KUN FÚN ÌGBOYÀ KÍ O SÍ LÒDÌ SÍ AIDARA-ẸNI-LOJU

IRÚGBÌN NÁÀ

“Ẹ jẹ ki a dì ijẹwọ ireti wa mu ṣinṣin li aiṣiyemeji; nitoripe olõtọ li ẹniti o ṣe ileri” Heb 10:23
Ọrọ mimọ yi kọ́wa ni ohun méjì pataki tí yíò mú wa yege gẹgẹ bí ọmọ Ọlọrun. Èkíní, o gbawa nimọran lati di ijẹwọ ìgbàgbọ wa mu ṣinṣin, ìgbàgbọ wa nínú Ọlọrun wipe ki yóò já wa kulè ti a ko bá já ara wa kulè. Ijẹwọ ìgbàgbọ wa ma n sọ ìgboyà wa di alagbara, nigbati ìgboyà wa ninu Oluwa ba l’agbara a ó lè e rin ọnà ìgbàgbọ lati gba ìbùkún wa. A o si le fi ìgboyà so wipe ‘Olorun wá ninu wa a kì yio ṣì wá nidi; Ọlọrun yíò ràn wá lọwọ ni kùtùkùtù òwúrò’. Èkejì, ọrọ mimi yìí bákanáà kìlọ fún wa nipa ṣíṣe iyemeji. O sọ wípé kí a jẹwọ ìgbàgbọ wa lai “ṣiyemeji”. Máṣe ṣiyemeji sí ara rẹ lati gba ìbùkún tí Ọlọrun ṣèlérí fún ọ. Gbe ara rẹ làruge ki o sí rin dédé níwájú Ọlọrun. Maṣe wo àlébù ara rẹ nitoripe ko le da ìlérí Oluwa duro, sugbon o le jẹ irin iṣẹ fún ọta lati mu ọ kọ oore Ọlọrun. Maṣe ṣeyemeji, yio mú ọ́rọ́ọ rẹ́wá sí imusẹ ninu ayé wa.
ÁDÙRÁ

Baba ni oruko Jesu, mo le gbogbo emi aidara-eni-loju jade, mọ sì gba ìgboyà láti rí ìbùkún mi gba. Amin.

BIBELI KIKA: Orin Dafidi 46:1-5

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *