Jesus The Provider

THE SEED
As soon as they were come to land, they saw a fire of coals there and fish laid thereon and bread. John21:9 KJV

Beloved, Jesus is your great provider. He has it all and if you will depend on him, you will never lack or be in need. He will supply all your needs, wants and luxuries. Beloved, do not look else where to get what you desire or struggle by your own strength and power. Sometimes when we attain a particular post we believe or think we have it all or it’s all by our strength and intellect. We are wrong! Only Jesus can do that for us. Look up to Jesus the provider, the Jehovah-Jireh. He shall always give more than enough even to your satisfaction. It’s all about Jesus and no one else. Just focus on him and all your needs and wants shall be sorted out to the glory of his Holy name. Only seek first the Kingdom of God and its righteousness and every other thing shall be added unto you.

BIBLE READING: John 21:9-14

PRAYER: Father, make me to always look up to Jesus, for in Him there is no lack.

JESU OLUPESE

IRUGBIN NAA
Ní kété tí wọ́n dé ilẹ̀ naa, wọ́n rí iná ẹ̀yinná níbẹ̀ àti ẹja tí ó tò lé e lórí àti búrẹ́dì Jòhánù 21:9

Olufẹ, Jesu ni olupese nla rẹ. O ni gbogbo nnkan ati pe ti iwọ ba gbekẹ re lee, iwọ kii yoo ṣe alaini. Oun yoo pese fun gbogbo awọn aini rẹ. Olufẹ, maṣe wo ibomiran nibiti iwọ yoo ti gba ohun ti o fẹ tabi tiraka nipasẹ agbara tirẹ. Nigba miiran, nigba ti a ba ni igbega de ipo kan, a maa n gbagbọ tabi ro pe a ni gbogbo rẹ tan tabi wipe nipasẹ agbara ati ọgbọn wa ni a Fi ni aseyori naa. Ko ri bee. Jesu nikan ni o le ṣe iyẹn fun wa. Wo Jesu Olupese, Jehofa-Jire. Oun nikan ni o le fun wa ju oun ti a nilo lo. Jesu nikan lo le se eleyi, ko si ẹlomiran. Sa a gbẹkẹle, gbogbo aini rẹ ni yoo yanju ninu ogo oruko re Mimo. Saa kọ́kọ́ wá ìjọba Ọlọrun ati òdodo rẹ̀, gbogbo nǹkan mìíràn ni a óo sì fi kún un fún yín.

BIBELI KIKA: Jòhánù 21:9-14 .

ADURA: Baba, je ki n ma wo Jesu nigba gbogbo, nitori ninu Re ko si aini.

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *