KNOWING GOD BEYOND MIRACLES

KNOWING GOD BEYOND MIRACLES

THE SEED

“He made known his ways unto Moses, his acts unto the children of Israel.” – Psalm 103:7 (KJV)

Miracles are powerful signs of God’s greatness, but they are not the ultimate goal of our walk with Him. The Israelites saw God’s mighty acts, yet they lacked intimacy with Him. Moses, however, sought to know God personally—and that relationship set him apart. God desires to reveal His character to us, not just His power. When we walk closely with Him, we grow in obedience, faith, and spiritual maturity. Miracles may sustain us for a moment, but intimacy with God transforms us for a lifetime.

BIBLE READINGS:  Exodus 33:12–23 (KJV)

PRAYER: Lord, help me to know You beyond Your acts. Draw me into deeper intimacy and reveal Your ways to me, in Jesus’ name. Amen.

NINI IMO OLORUN TAYO ISE IYANU

IRUGBIN NAA

O fi ọ̀na rẹ̀ hàn fun Mose, iṣe rẹ̀ fun awọn ọmọ Israeli. Orin Dafidi 103:7

Ise iyanu je amin titobi Olorun, sugbon kiise tori re ni a se nba rin. Awon omo isreli ri ise nla Olorun sugbon won o ni ibasepo pelu re. Mose gbiyanju lati mo Olorun fun ara re, ibasepo yi si yaa soto. Olorun fe lati fi iwa re han wa , kiise agbara re nikan. Ni gba ti a ba rin sunmoo, ao dagba ninu igboran, igbagbo ati idagbasoke tie mi. ise iyanu le mu wa duro fun igba die sugbon ibasepo pelu Olorun lo ma yi wa pada titi ayeraye.

BIBELI KIKA: Eksodu 33:12-23

ADURA: Oluwa, Ranmilowo lati mo o tayo awon ise re. fa mi sinu ibasepo ti o jin, ki o si fi ona re han mi ni oruko Jesu. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *