Knowing God II

THE SEED
…looking unto Jesus, the author and finisher of our faith, who for the joy that was set before Him endured the cross, despising the shame, and has sat down at the right hand of the throne of God. Heb. 12:1-2 NKJV

Thanks be to God for the truly wonderful Ministers of God we have in Christendom, that have and remain an example for us all with their faith, obedience and love for God. Hallelujah to God for the Saints of old and the ones we read of in the Bible. However we must keep in mind that in this race of life, the one person we are truly looking up to is Jesus Christ Himself. He alone is the Author and the Finisher of our faith. Failure to comprehend this is the reason why many believers in the past and in the years to come, allow unscrupulous leaders lead them into error and sin. Man is imperfect and fallible, but Jesus is not. Take examples around you, but keep your eyes on Jesus.

PRAYER
Heavenly Father, help me to keep my eyes fixed on you, in Jesus name Amen.
BIBLE READINGS:  Heb. 12: 1 – 2 NKJV

   MIMO OLORUN (KEJI)

IRUGBIN NAA
Kí a máa wo Jesu Olùpilẹ̀ẹ̀ àti aláepé ìgbàgbọ́ wa; ẹni nítorí ayọ̀ tí a gbé ka iwájú rẹ, tí o faradà àgbélébùú láìka ìtìjú sí, tí ó sì jókòó lọ́wọ́ ọ̀tún ìtẹ́ Ọlọ́run. Heberu 12:2

A dupe ni owo Olorun fun awon ojise Oluwa tooto, ti won n fi iwa igbagbo, igboran ati ife si Olorun se awokose rere fun wa. Alleluya si Olorun fun awon eniyan mimo igbani. Sibe, a gbudo mo daju wipe ninu irin ajo aye yii, eni kan ti a gbodo maa wo ni Jesu Kristi funra re. Oun nikan ni Olupilese ati Alasepe igbagbo wa. Aini oye yii ni o n mu ki awon onigbagbo miran fi aye gba awon olori won lati ti won sinu asise ati ese. Eniyan pipe kan ko si, beeni eniyan le subu, Jesu nikan ni ko ni isubu. O lee ni awokose, sugbon Jesu ni ki o maa wo.

ADURA
Baba orun, ranmi lowo lati maa wo iwo nikan ni oruko Jesu. Amin.
BIBELI KIKA: Heberu 12: 1-2

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *