THE SEED
“Also I heard the voice of the Lord, saying: ‘Whom shall I send, and who will go for Us?’ Then I said, ‘Here am I! Send me.” Isaiah 6:8
Elijah was sent to confront the evil king of Israel, Ahab. At God’s request, Elijah boldly declared that there would be no rain or dew on the land of Israel until the word was spoken. He threw a gauntlet into a country where Baal was being served, a god who claimed to have brought down the rain and cultivated crops. Elijah challenged Baal and showed the true power of God. Three and a half years later, the drought devastated Israel. Elijah stood on God’s Word. He did what God asked him to do, and he made it count. No matter how difficult the task that God has given you, make it count. No matter how many or how few stand with you, make it count.
If He sends you into political office, speak the declarative words of truth. He can send you to a PTA, your workplace, or a community center. He may ask you to lead the choir or sing in the choir. No matter what you do, make it count! Elijah stood in a generation where no one else was willing to tell the truth. The country knelt, as he did. Get ready to go. Get ready to stand. Get ready to speak. Let it count!
PRAYER
Heavenly Father bestow upon me grace and power to let your word inside me count at the places Your name will be glorified Amen.
BIBLE READINGS: 1 Kings 17: 1-6; 1 Kings 18
JE KO NI IPA
IRUGBIN NAA
“Emi si gbo Ohun Oluwa wipe, tali emi o ran, ati tani yio si lo fun wa? Nigbana li emi wipe, Emi niyi, ran mi.” Isaiah 6:8
A ran Elijah si oba Ahabu, eniti o se eyi ti o buru li oju Oluwa, gege bi ase Olorun, Elijah fi igboya wipe ki yio si ojo tabi iri ni ile naa. Eyi mu isoro ba orile ede ti won ti n sin baali, orisa ti won gbagbo wipe on ni o maa n rojo ti won fi ndako. Elijah pe baali nija, o si fi agbara otito ti nse ti olorun han, leyin odun meta, osu mefa, ogbele naa lagbara ni Isreali. Elijah duro lori oro Olorun, o se eyi ti Olorun palase fun lati se, o si je ki o ni ipa. Bi o ti wu ki ise ti Olorun ran o le to, je ki o ni ipa, ko ni fi se iye awon ti o duro ti o tabi ti o ko o sile, je ko ni ipa. Bi o ba ran o si ile ise Oloselu, So oro otito, o le ran o lo si ipade obi ati oluko, ibi ise re, tabi agbegbe re. o le dari re lati korin tabi dari orin ninu akorin, ohunkohun ti o ba se, je ki o ni ipa. Elijah duro ni iran ti ko si eni ti o fe so otito. Orile ede naa si wole nigba ti o se bee. Mura sile lati lo, mura sile lati duro, mura sile lati soro. Je ko ni ipa.
ADURA
Baba mi orun, fun mi ni oore ofe ati agbara lati je ki oro re ninu mi ki o ni ipa ni ibi gbogbo. Amin
BIBELI KIKA: 1 Awon Oba 17: 1-6; 1 Awon Oba 18