LET YOUR CONFIDENCE BE IN GOD

 

LET YOUR CONFIDENCE BE IN GOD

THE SEED  

“I can do all things through Christ which strengtheneth me.” Philippians 4:13.  

As we have entered a new century, with the advent of technology and scientific  breakthroughs, man appears to have become smarter and quicker in the way things are being  done and there seems to have been a change in our view of life and our environment at large.  

The society at large now begins to emphasise the capacity and ability of man in  achieving whatever he wants to achieve. But God‘s factor is key in man’s activities. It’s God that  gave the intellectual knowledge and raw materials to pursue all the technology and scientific  advancement and it is by God that our good intentions are being actualised.  

In the book of Deuteronomy 8:18; Moses told the children of Israel, “But thou shall  remember the Lord thy God: for it is He that giveth thee power to get wealth, that he may  establish his covenant which he swears unto thy fathers, as it is this day. In that they should  never think that their power and the might of their hand gave them their wealth.” Let your confidence be in the Lord and not in your ability or influence. 

PRAYER 

May my confidence be built on nothing else but on the solid rock of Christ in Jesus name. Amen. BIBLE READINGS: Deuteronomy 8:11-19 

JEKI IGBOYA RE WA NINU OLORUN 

IRUGBIN NAA 

“Èmi lẹ e ohungbogbo ninu Kristi eniti o nfi agbara fun mi.” Filipi 4:13 

Bi a ti e wọ ọgọrùn ọdún miran pẹlu ifarahan ìmọ ẹrọ ati ijinlẹ sáyẹnsì, awọn eniyan ni  ọgbọn òye àti iyàrá lati e ohùn ti wọn fẹ e. Ìmọ ti o gbórò sí tun wà láti mú ìlọsíwájú àti  ayípadà wà fún ayika wà. 

Ènìyàn lápapò bẹrẹ sí ní jẹ gaba lórí ipá àti agbára tí wọn ní láti fẹ àti láti ní ohun tí wọn  pinnu lati e. ugbọn alakale Ọlọrun e kckc nínú ipá ènìyàn. 

Ọlọrun ni o fun ènìyàn ní ìmọ ijinlẹ àti àwọn ohun èlò láti lè e ìmọ ẹrọ ati ohun ijinlẹ sáyẹnsì. Nipa Ọlọrun sí ní ohun gbogbo wọnyi e wà sí imusẹ 

Nínú ìwé Deuteronomi 8:18 Mósè sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé “ugbọn kí iwọ kí o rántí  Olúwa Ọlọrun rẹ: nítori pé Òun ní o fun o ní agbára láti li ọrọ ki Òun kí o le fí ìdí majemu Rẹ ti o  búra fun awọn bàbá rẹ kalẹ bí o tí rí li oni yí ”  

ADURA 

Jeki igboya mi ma wa ninu ohun miran bikose apata Kristi in oruko Jesu. Amin BIBELI KIKA: Deuteronomy 8:11-19 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *