THE SEED
“Watch ye therefore and pray always, that ye may be accounted worthy to escape all these things that shall come to pass and to stand before the Son of man” Luke 21: 36
Living a relationship with Christ goes beyond church-going as many believe. A lot also believe answering the name Christian automatically makes them qualified among the group of people recognised by the Holy Spirit to have a living relationship with Christ. The truth is, having a living relationship with Christ is when you keep the fire burning, and let your character show that you have Jesus beside you. Many people display a nonexistent relationship with Christ in church, before pastors, in and amid people. These are also inclusive but the real question is do you keep the fire burning, even when there is no one around you? God looks at the heart. For man looketh on the outward appearance but the Lord looketh on the heart. Many already lost it and many are losing it because they thought they had a relationship with Christ but the truth is they have no living relationship and anything that is not living is dead. To maintain a living relationship with God, we must be conversant with the Words of God and constantly do what it says. Prayers, giving, evangelism, love and many more; most importantly, have a clean heart. When your relationship with God is alive and active, whenever you call on Him he is always ready to answer you because He sees you as a true and legitimate child who would be able to escape the evil of this world and stand before the Son of man. Ignite the fire in the relationship that you have with Christ today and your life will never remain the same.
BIBLE READING: John 15:4-8
PRAYER: May the Lord give you the spirit and strength to keep your relationship with him alive always, Amen.
ÌBÁṢÈPỌ PẸ̀LÚ KRISTI
IRUGBIN NAA
“Njẹ kí ẹ máà ṣọ́na, ki ẹ sí màá gbadura nigbagbogbo, ki ẹ bá lè la gbogbo nkan wọ̀nyí tí mbọ̀ wá ìṣe kí ẹ sí lé dúró níwájú Ọmọ ènìyàn”. LUKU 21:36.
Níní ìbáṣèpọ ̀pẹ̀lú Kristi kọjá lílọ jọ́sìn nínú ìjọ kan gẹ́gẹ́ bí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ṣè gbagbọ́. Pupọ tun gbagbọ pe idahun pé Kristẹni ni awọ́n, jẹ ki wọn ro pe; nígbàtí awọ́n peye lai yẹ wọ́n wò laarin ẹgbẹ àwọn eniyan ti a mọ nipasẹ Ẹmi Mimọ ti o ni ìbáṣèpọ pẹlu Kristi. Otitọ ni pe, nini ìbáṣèpọ ààyè pẹlu Kristi ni ji jẹ ki ina ẹmi maa jó, ati ki o si jẹ ki iwa rẹ fihan pe o ni Jesu lẹgbẹ rẹ. Ọpọlọpọ eniyan nṣe afihan ìbáṣèpọ ti ko ni ohunkóhun ìṣe pẹlu Kristi ni ile ijọsin, niwaju awọn oluso-aguntan ati laarin awọn eniyan. Iwọnyi tun wa pẹlu, ṣugbọn ibeere to daju ni pe Ṣe O JẸ́KÍ INA NJO BI O TILẸ JẸ́ PÉ KO SI ENIYAN NI ÀYÍKÁ RẸ̀? Ọlọ́run nwo ọkàn. Ṣùgbọ́n ènìyàn a máa wo ojú ṣùgbọ́n Olúwa a máa wo ọkàn. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ti pàdánù rẹ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ sì ń pàdánù rẹ̀ nítorí wọ́n rò pé àwọn ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Kristi; ṣùgbọ́n òtítọ́ ni pé wọn kò ní ìbáṣepọ̀ ÀÀYÈ, ohunkohun tí kò bá sì wà láàyè ti di òkú. Láti le mu ki ìbáṣèpọ wa pẹlu Ọlọrun wa laaye, a níláti wà pẹlu awọn ọrọ Ọlọrun nigbagbogbo ki a sí máà ṣe ohun ti o sọ: bí i awọn àdúrà gbigba, ifi funni, ihinrere, ifẹ ati ọpọlọpọ bẹ ẹ sii; Ni pataki julọ ki a ni ọkan mimọ. Nigbati ìbáṣèpọ rẹ pẹlu Ọlọrun ba wa laaye ti o si nṣiṣẹ, nigbakugba ti o ba pe e, o mura tan nigbagbogbo lati da ọ lohun, nitori pe o ri ọ bi ojúlówó ọmọ tootọ ti yíò ni anfani lati sa fun iwa ibi inu aiye yi; ki o si duro niwaju Ọmọ-ènìyàn. Mu ki ina ti o wa ninu ìbáṣèpọ ìwọ pẹ̀lú Kristi ki o máa jó loni, ìwọ yio si ri pe aye rẹ̀ ki yíò wa bakanna mọ.
BIBELI KIKA: Johanu 15:4-8.
ADURA: Ki Oluwa fun o ni ẹmi ati agbara lati jẹ́kí àjọṣepọ̀ Rẹ̀ pẹ̀lú rẹ wa laaye nigbagbogbo. Amin.