Mercies Of The Lord

THE SEED
It is of the Lord’s mercies that we are not consumed, because his compassions fail not. Lamentations 3:22

There is One who rules over all human matters and observes all we do. His throne is in heaven. He doesn’t alternate between showing mercy and passing judgement. Our heavenly Father is kind at all times. An act of divine favour or compassion, mercy is a blessing. We are truly spared of destruction, because of God’s compassion. God’s mercies never end (Psalms 136:1). Jesus Christ, who never committed a sin, was sent by God’s mercy to die in place of all human sin. Jesus Christ may save the murderer, thief, prostitute, alcoholic, liar, etc. because of the grace of God. Dearly beloved, God’s mercies are available to you, no matter where you are or what you have done because He never loses compassion. Benefit from God’s mercies and you will be blessed. God’s mercies can rescue you from squalor and set you among royalty (2 Samuel 9:1-13). Jesus Christ was a compassionate individual (Matthew 9:36). Because it is as timeless as it is timeless and as trustworthy as it is dependable, God’s kindness never fails!

PRAYER
O Lord, save me from all unrighteous ness, count me among your royals, let me receive mercy in your sight. Amen.
BIBLE READINGS:  Lamentations 3

  AANU OLUWA

IRUGBIN NAA
Aanu Oluwa ni ti awa ko parun tan, nitori ironu aanu re ko ni opin ni. Ẹkun Jeremiah 3:22

Eni kan wa ti o joba lori gbogbo ohun ti o je mo ti eniyan ti o sin n ki ye si ohun gbogbo ti a n se. Itẹ Rẹ mbẹ li ọrun. Kii  se pasiparo aanu ati idajọ. Baba wa ọrun jẹ oninurere ni gbogbo igba. Iṣe oju-rere tabi aanu atọrunwa jẹ ibukun. A yo wa kuro ninu iparun nitootọ nitori ojurere Ọlọrun. Aanu Ọlọrun ko lopin (Orin Dafidi 136:1). Jésù Kristi, tí kò dá ẹ̀ṣẹ̀ rí, ni a rán nipa àánú Ọlọ́run láti kú dípò ẹ̀ṣẹ̀ ènìyàn. Jesu Kristi le gba apaniyan, ole, panṣaga eniyan, ọmuti, oniro, ati bẹbẹ lọ nitori oore-ọfẹ Ọlọrun. Olufẹ, aanu Ọlọrun wa fun ọ, ni ipokipo ti o ba wa nitori ti Oluwa ko ni se alai saanu fun o, ko ni fi se ohun ti o ti se sehin. Je anfani aanu Ọlọrun, iwọ yoo di alabukun fun.. Aanu Ọlọrun le gba ọ kuro lọwọ ẹgan ki o si fi ọ sinu ola (2 Samueli 9: 1-13). Jésù Krístì jẹ́ oníyọ̀ọ́nú ènìyàn (Matteu 9:36). Olorun wa je ayeraye, Osi je olotito ati eni ti ose gbekele. Aanu Oluwa kii  jani kule.

ADURA
Oluwa, gba mi lowo aisedede gbogbo, ka mi mo awon omo re, je ki n ri aanu gba niwaju re. Amin.
BIBELI KIKA: Ekun Jeremiah 3

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *