Spiritual Fire

THE SEED
For I, saith the LORD, will be unto her a wall of fire round about, and will be the glory in the midst of her. Zechariah 2:5

Moses and the body of Christ both experienced the fire of the Holy Spirit and the glory, and both experiences are identical. God’s character is one of glory. Our God is like a raging fire. If this is the case, anything that is not of God will be burned away by the fire of the Holy Spirit, from your workplaces, bodies, homes, and children’s lives. If you think it’s true, stand up and give God praise! God’s Word is like fire. There are glory encounters in the Word. “Your Word was like a fire in my bones,” Jeremiah 20. These days, we are dealing with it, and when we read the Bible, we sense His fire consuming us. Our spirits are flammable, and the Word is the source of the spiritual fire. When the Word of God enters our hearts, it burns. Even more potent than rocket fuel, the Word of God is a spiritual fuel. Let’s keep stocking the fire by supplying it with words from the Bible and persistent prayer. Keep an open mind so the wind of the Holy Spirit can fan the fire into a roaring blaze. From now on, let this Word smoulder inside you.

PRAYER
O Lord, let your word continue fill me, and increase your spiritual fire inside me. Amen.
BIBLE READINGS:  Zechariah 2:1-7

   INA EMI

IRUGBIN NAA

Oluwa wipe, Emi yio si je odi ina fun yika, Emi yio si je ogo. Sekaria 2:5

Mose ati ijo Kristi pelu ni iriri ina ti Ẹmi Mimọ pelu ogo, awọn iriri mejeeji fi ara pe ra.. Iwa Ọlọrun jẹ ti ogo. Ọlọ́run wa dà bí iná tí ń jó. Ti o bá rí bẹ́ẹ̀, ohunkóhun tí kì í ṣe ti Ọlọ́run ni a o o jo pelu iná Ẹ̀mí, yala ní ibi iṣẹ́, ara, ilé àti ti igbesi aye àwọn ọmọ. Ti o ba ro pe otitọ ni eyi, dide ki o si fi iyin fun Ọlọrun! Oro Olorun dabi ina. Awọn iriri ogo wa ninu Ọrọ. “Ọrọ rẹ dabi iná ninu egungun mi,” Jeremiah 20. Ni akoko yi, a ni iriri rẹ, nigba ti a ba ka Bibeli, a o rii iriri ina Olorun.  Emi wa jẹ ina, ati pe Ọrọ Olorun ni orisun ina Emi. Nigbati Ọrọ Ọlọrun ba wọ inu ọkan wa, yio ma jo. O ni agbara ju o un ija lọ, Ọrọ Ọlọrun njẹ ki Emi ru soke. Ẹ jẹ́ ki ina Emi maa jo nipa kika oro Olorun ninu Bibeli  àti àdúrà àisare. Sipa ya ọkàn rẹ̀ sílẹ̀ kí ina Ẹ̀mí Mímọ́ lè jo gere ni inu re. Lati isinsin yi lọ, jẹ ki Ọrọ yii jó ninu re.

ADURA
Oluwa, je ki oro re ki o kun inu mi, ki o si je ki ina Emi re posi ninu mi. Amin.
BIBELI KIKA: Sekaria 2:1-7

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *