Miraculous And Dependable God

THE SEED
“But my God shall supply all your needs according to His Riches in Glory by Christ Jesus.” Philippians 4:19

This world is difficult to live in but we have a Father in Heaven who has promised us that He will always provide a way for us out of all our problems and that He will not allow any temptation that is beyond our capability to befall us. It is profitable to be upright before God always. A man of God died leaving wife and children but he owed some amount of money before his demise, then the owner of the debt didn’t have a choice than to take the children away to work for him to offset it, but the wife ran to another man of God and explained things to him but mentioned that ” the late husband feared the Lord”. Anyone that fears the Lord will solely depend and rely on Him for every step he takes, he will not waiver to the left or the right. The prophet then prophesied and blessed the little oil the woman had in the house to make multiple big pots of oil which she sold, used to pay the debt and had rest to herself and her children. Anybody that depends on God will never be put to shame. Learn to rely and depend on God for everything.

BIBLE READING: 2 Kings 4:1-7

PRAYER: I pray, the tribulations that will make us run Helter skelter, forgetting that God is all in all for us will not befall us in Jesus Name. Amen

ỌLỌRUN IYANU TO TO GBEKELE

IRUGBIN NAA
Sugbon Olorun mi yio pese gbogbo aini yin gege bi oro re ninu Ogo ninu Kristi Jesu. Fílípì. 4:19

Ayé yìí ṣòro láti gbé, ṣùgbon a ní Bàbá ní orun tí ó ti ṣèlérí pé òun yóò pèsè onà abayo fún wa kuro nínú gbogbo ìṣòro wa àti pé Òun kì yóò je kí ìdánwò èyíkéyìí tí ó ju agbára wa lọ láti bá wa. Èrè ló je láti dúró ṣinṣin níwájú Ọlorun nígbà gbogbo. Okunrin Olorun kan ku ti o fi iyawo ati awon omo sile sugbon o je owo die ki o to ku. Bee ni eni ti won je ni gbese naa ko ni ipinnu ju ki o ko awon omo naa lo lati sise fun un lati Fi San gbese won sugbon iyawo naa lo ba enìyàn Ọlorun mìíràn ó sì ṣàlàyé oun ti o sele fún un. Nínú alaye re, o so wipe “ọkọ oun berù Olúwa”. Ẹnikeni tí ó bá berù Olúwa yóò gbekere lé ni gbogbo ìgbése tí ó bá gbé. Ko ní yà sí òsì tàbí sotun. Wòlíì náà wá sọ tele, ó sì gbadura si òróró kékeré tí obìnrin náà ní nínú ilé láti so o di opo òróró nínú awon ikoko re eyi tí ó tà, tí ó SI fi san gbèsè náà, ó sì ní ìsinmi fún ara re ati àwọn ọmọ re. Ẹnikeni tó bá gbeke lé Ọlorun, oju ki yio tii. Kọ ẹkọ lati gbẹkẹle Olọrun ninu ohun gbogbo.

BIBELI KIKA: 2Àwọn Ọba 4:1-7

ADURA: Mo gbadura, inira ti yoo mu wa sare odi, ti yio mu wa gbagbe Olorun ki yoo ba wa loruko Jesu. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *