NO KING ABOVE THE KING
THE SEED
“‘Do not be afraid of the king of Babylon, of whom you are afraid; do not be afraid of him,’ says the Lord, ‘for I am with you, to save you and deliver you from his hand.’” Jeremiah 42:11 (NKJV)
Throughout history, God has consistently defeated every power that rose against His people. He delivered Israel from Pharaoh, saved baby Jesus from Herod, and preserved Judah from the king of Babylon. His power has no equal. There are modern-day “kings” — fear, shame, barrenness, delay, oppression, and sickness — that try to terrorize our lives. But the same God who fought then still fights for His children today. Beloved, do not bow to fear. Let God take over the battles that seem too strong for you. When He steps in, no king can stand against Him.
Reflection: No enemy is greater than the God who fights for us.
BIBLE READING: Jeremiah 42:10–12
PRAYER: Father, silence every king contending against my life. Fight my battles and give me victory. Amen.
KÒ SÍ ỌBA TÓ GA JÙ ỌBA NÁÀ
IRUGBIN NAA
“Ẹ má bẹ̀rù ọba Bábílónì, ẹni tí ẹ̀ ń bẹ̀rù rẹ̀; ẹ má bẹ̀rù rẹ̀,” ni Olúwa wí, “nítorí mo wà pẹ̀lú yín, láti gbà yín là àti láti gbà yín kúrò lọ́wọ́ rẹ̀.” – Jeremáyà 42:11
Ninu gbogbo itan, Ọlọ́run ti ṣẹ́gun agbára tí ó dìde sí àwọn ènìyàn Rẹ̀ nígbà gbogbo. Ó gba Ísírẹ́lì là kúrò lọ́wọ́ Fáráò, ó gba Jésù nigba ti o wa ni ọmọ owo kúrò lọ́wọ́ Hẹ́rọ́dù, ó sì pa Júdà mọ́ kúrò lọ́wọ́ ọba Bábílónì. Agbára Rẹ̀ ko duro, o si wa bakannaa. Àwọn ọba òde òní wà b ìbẹ̀rù, ìtìjú, àìlóyún, ìfàsẹ́yìn, ìnilára, àti àìsàn tí ó ń gbìyànjú láti dẹ́rù ba ìgbésí ayé wa. Ṣùgbọ́n Ọlọ́run kan náà tí ó njà nígbà náà ṣì ń jà fún àwọn ọmọ Rẹ̀ lónìí. Olùfẹ́ mi, ẹ má tẹrí ba fún ìbẹ̀rù. Jẹ́ kí Ọlọ́run gba àwọn ogun tí ó dàbí ẹni pé ó lágbára jù fún yín. Nígbà tí Ó bá wọlé, kò sí ọba tí ó lè dúró lòdì sí I.
ÌRONU: Kò sí ọ̀tá tí ó tóbi ju Ọlọ́run tí ó ń jà fún wa lọ.
BIBLE READING: Jeremáyà 42 :10-12
PRAYER: Bàbá, pa gbogbo ọba tí ó ń bá ẹ̀mí mi jà lẹ́nu mọ́. Ja ogun mi kí o sì fún mi ní ìṣẹ́gun. Àmín.