NOTHING NEW UNDER THE SUN

NOTHING NEW UNDER THE SUN

THE SEED

“Whatever is has already been, and what will be has been before; and God will call the past to account.” — Ecclesiastes 3:15 (NIV)

Human ambition is not new. Many have achieved greatness and left the stage; others will do so after us. Earthly achievements fade, but what is done for God endures. This truth should shape how we pursue our dreams—with humility and an eternal mindset. A wise believer does not chase temporary glory but builds with eternity in view. God rewards only what aligns with His will. Use your time and gifts to make eternal impact. Build legacies that point others to Christ, not just personal glory.

Reflection: Earthly achievements fade, but godly pursuits endure.

 

BIBLE READING: Ecclesiastes 3:14–17

PRAYER: Father, help me pursue dreams that bring glory to You and have eternal value. Amen.

 

KO SI OHUN TUNTUN LABE ORUN

IRUGBIN NAA:

“Ohun ti o wa ri, nbe nisinsinyi; eyi ti yoo si wa, o ti wa na; Olorun si se eyi ki eniyan ki o le ma beru re.” Oniwaasu 3:15

Ilepa eniyan kii se ohun titun. Opo lo ti de ibi giga ti won si ti lọ, awon miiran yoo tun se bee gege leyin awa naa. Aseyege ti aye maa nṣá, sugbon ohun ti a ba nse fun Olorun ni kii ṣá. Otito yi ni ki o se amona bi a ti nlepa afojusun wa; pelu irele ati okan ti o te si iye ainipekun. Onigbagbo ologbon ki i le ogo ranpe sugbon a maa sise pelu iye ainipekun ni okan re. Olorun maa nsan esan fun ohun ti o ba ba ife Re mu nikan. Fi akoko ati ebun re sise ti o ni ipa ti yoo duro titi lai. Gbe igbe aye ti ntoka awon eniyan si Kristi, ki i se si ogo ara re.

Asaro: Aseyege aye maa nsa, sugbon lilepa awon ohun ti Olorun maa duro titi lai.

 

BIBELI KIKA Oniwaasu 3:14-17

ADURA: Baba, ran mi lowo lati lepa awon ohun ti yoo bu ogo fun O, ti yoo si ni iyi ayeraye. Amin.

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *