Only God Can Do What No Man Can Do

THE SEED
“And He said unto me, son of man, can these bones live? And I answered, O Lord God, thou knowest” Ezekiel 37: 3(KJV)

There is nothing difficult for God to do. He is a protocol breaker, and nothing surpasses His power, all troubles and challenges of life we face each day can be taken care of within a twinkle of an eye. If God Almighty can breathe onto the dead bones through Prophet Ezekiel and they heard the voice of God to become alive. Our situation can never be different, He is the God of all flesh, it is just for us to realize who He is, rely on and trust in Him always, pray without ceasing and Obey all instructions to the least. Do not say Grace will speak for you, it doesn’t work like that, that is exactly where the Israelites missed it, they always disobey God, I pray we shall always find favour in His Presence if we listen and obey. He is ever ready to meet us at the point of our needs, He promised He will provide for all our needs according to His riches in glory through Christ Jesus.

PRAYER
I pray today that every dry bone in my life shall receive the breath of God to live again in Jesus’ Name. Amen
BIBLE READINGS:  Ezekiel 37:1-6

  ỌLORUN NIKAN LO LE SE OHUN TI ENIYAN KO LE SE

IRUGBIN NAA
“Ó sì wí fún mi pé, ọmọ ènìyàn, é àwọn egungun wonyí lè yè bí? Emi si dahùn pe, Oluwa Ọlọrun, iwọ mọ̀” Esekiẹli 37:3 (KJV)

Ko si ohun ti o soro fun Olorun lati se. Oun lo le yi  ilana pada, ko si si ohun ti o kọja agbara Rẹ, gbogbo awọn wahala ati awọn idojuko ti a  n koju lojoojumọ ni a le ṣe abojuto laarin iseju aaya.. Bí Ọlorun Olódùmarè bá lè mí sí àwọn egungun òkú nípasẹ̀ wòlíì Ìsíkíelì tí won sì gbo ohùn Ọlorun láti di alààyè. Tiwa ko le yatọ rara, Oun ni Ọlọrun ti gbogbo eran Ara, awa ni ki a mo ẹni ti O jẹ, gbekele  nigbagbogbo, gbadura laisi Simi ati ki o si gbonran si gbogbo itosona re. Maṣe sọ pe oore-ọfẹ yoo was fun ọ, ko ṣiṣẹ bẹ, Nítorí eyi ni awọn ọmọ Israeli  se padanu, wọn ṣe aigbọran si Ọlọrun nigbagbogbo. Mo gbadura pe a oo ri ojurere nigbagbogbo niwaju Rẹ ti a ba gbọ ti a si tele. O ti setan Lati yanju awọn aini wa. O ṣe ileri pe Oun yoo pese fun gbogbo aini wa gẹgẹ bi ọrọ Rẹ ninu ogo nipasẹ Kristi Jesu.

ADURA
Mo gbadura loni pe gbogbo egungun gbigbe ninu aye mi yoo gba imi Olorun lati tun wa laaye loruko Jesu. Amin
BIBELI KIKA: Ìsíkíelì 37:1-6

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *