Preparation For The Gospel Of Peace

THE SEED
And having shod your feet with the preparation of the gospel of peace. Ephesians 6:15

We are all called to tell others of the Good News of salvation. Sharing the Good News of the Gospel is the most important task of every Christian, not just for Evangelists, Pastors or Preachers. Each of us have contact with people whom no one else can reach and if we pay attention to the guidance of the Holy Spirit, we can be efficient workers in the “Lord’s Vineyard.” Telling others about our Lord Jesus Christ is not only for their benefit, but for ours also. As we realize that others are looking at how we live, talk and act, we are more inspired to do our best and become more and more like Christ. Studying the Scriptures and spending time with the Holy Spirit, giving Him time to reveal to us the mysteries of God are essential for us to be able to disciple others and give them the right biblical advice.

BIBLE READING: EPH 6, JOHN 14

PRAYER: Lord, I pray for all those I have ministered to but did not receive You yet. Continue to touch their hearts and help them realize how much You love them and how they need to renounce sin and follow You. Glory and honor to Your holy Name, for ever and ever, Amen.

ÌMÚRASÍLẸ̀ FÚN ÌHÌN RERE ÀLÀÁFÍÀ

IRUGBIN NAA
Àti pé ẹ ti fi ìmúrasílẹ̀ ìhìn rere àlàáfíà wọ ẹsẹ̀ yín; Éfésù 6:15

Gbogbo wa ni a pè láti sọ ìhìn rere ìgbàlà fún ẹlòmíràn. Pipin Ihinrere jẹ iṣẹ pataki julọ fún gbogbo onigbagbọ, kii ṣe fun awọn ajihinrere, olusoagutan tabi awọn oniwaasu nikan. Olukuluku wa ni o ni olubasọrọ pẹlu awọn eniyan ti ẹlomiran ko lee de ọdọ wọn: ati pe bi a ba fi ara balẹ fún itọsọna ti Ẹmi Mimọ, a le jẹ oṣiṣẹ daradara ninu “Ọgbà-àjàrà Oluwa.” Sisọ fun awọn ẹlomiran nipa Oluwa wa Jesu Kristi kii ṣe fun anfaani wọn nikan ṣugbọn fun anfaani ti wa pẹlu.Bi a ṣe mọ pe awọn ẹlomiran n wo bi a ṣe n gbe igbe aye wa, isọrọ wa, ati iṣe wa, eyi ru wa sókè láti ní itara diẹ sii, lati le ṣe ohun ti o dara julọ ki a le dabi Kristi. Kíkọ́ iwé mímọ́ àti lílo àkókò pẹ̀lú Ẹ̀mí Mímọ́, fífún ni àkókò láti fi àwọn ohun ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run hàn fún wa ṣe pàtàkì fún wa láti lè sọ àwọn ẹlòmíràn di ọmọ ẹ̀yìn kí a sì fún wọn ní ìmọ̀ràn Bibeli títọ́.

BIBELI KIKA: Efesu 6, Johanu 14

ADURA: Oluwa, mo gbadura fun gbogbo awọn ti mo ti ṣe iṣẹ iranṣẹ fun; ṣugbọn ti wọn ko tii gba Ọ. Ẹ́ tẹsiwaju lati fi ọwọ kan ọkan wọn, ki o si ran wọn lọwọ lati mọ bi O ṣe nifẹ wọn; ati bi wọn ṣe nilo lati kọ ẹṣẹ silẹ lati tẹle Ọ. Ogo ati ọla fun Orúkọ mimo Rẹ lae ati laelae, Amin.

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *