Preparing To Meet With God

THE SEED

“A voice cries out, “Prepare in the wilderness a road for the Lord! Clear the way in the desert for our God!” Isaiah 40:3 GNT

Our essence of living a Christian life is all about preparation to be welcomed by Almighty God at the end of our lives here on earth, whether by death or rapture. The fact that these two conditions are unpredictable gives no room for slacking around. We are to be always getting ready. Another way to look at this preparation is our taking time out to spend time with God in His presence. We need to prepare a road for the Lord to walk through in the wilderness of our hearts, that is encumbered with worries and challenges. We must clear the way in our life’s desert created by sin. Do this look like something daunting? It’s yes if you don’t know what to do, but it’s also simple! Here is the solution, make the way in your wilderness by ejecting any doubt from your mind and believing wholeheartedly that God is able. This will make you ready and receptive to receive your deliverance when the Lord is passing through. The only mountain that can stand after God’s move is the one created by your doubt. Also, the desert will be replaced with fruitfulness when you confess, and renounce all committed sins without reservations. Then, the breath of God will move to bring you back to life and make things anew.

PRAYER

Lord Jesus, help me to be able to make a way for you in the wilderness and desert of my life so that I can receive a total deliverance. Amen

BIBLE READINGS: Isaiah 40:3-5

ÌPALẸ MỌ LATI PÀDÉ ỌLỌRUN

IRÚGBÌN NÁÀ

“Ohùn ẹniti nkigbe ni ijù, ẹ tún ọ̀na Oluwa ṣe, ṣe opópo titọ́ni aginjù fun Ọlọrun wa.”Isa 40:3

Ìdí ti a fi n gbé igbe aye Kristẹni ni lati ṣe imurasilẹ fún gbígbà wá wọle si ọ̀dọ̀ Ọlọrun nikẹhin ayé wa yálà nípa ikú tabi igbasoke awọn ayanfẹ. Awọn ìdí meji wonyi jẹ́ohun tí a kòlè sọ ìgbàtí wón le ṣẹlẹ, nitorina a ni lati wa ni imurasile nigbagbogbo. Ọnà míràn láti wo imurasilẹ yi ni nipa ipalẹmọ wa gẹgẹ bí ẹnìkan, tọkọtaya, ẹbí, egbe awon onigbagbo, tabi Ìjọ, lati ni akoko iyasọtọ níwájú Ọlọrun. Ọrọ Ọlọrun ti o wà lókè yí jé itọnisọna ti o le ran wa lọwọ lati ṣ’eto ọnà tí Oluwa yíò tí rìn nínú aginjù ọkàn wa ti o kún fún àníyàn, a ní lati fi àyè sílẹ nínú aye wa eyi ti o kún fún àwọn ìrírí ibalọkanjẹ. Nje èyí kò jẹ ìṣòro lati ṣe? Idahun ni wípé, bẹni, ti a ko ba mọ ohun ti o tọ́láti ṣe, sugbon kòsì tun ṣóro! A o lana ninu aginjù wa nípa lílé iyeméjì jade kúrò nínú ọkàn wa ki a sí gbàgbọ́wipe Olorun le ṣe ohun gbogbo, nipa eyi a o ṣetan lati gba idande nigbati Oluwa ba nla aginjù aye wa kọja. Òkè kan ṣoṣo tí o lē duro níwájú Ọlọrun ni oke ti a fi iye meji gbe duro. Bakanna, èso réré yio hun ninu aṣálẹ wa nígbàtí a bá jẹwọ ti a sì kọ gbogbo ẹsẹ wa silẹ, nigbana ni ēmi Olorun yíò wò inu àìlera wa láti fún wa ní ìyè tí yíò sọ ohun gbogbo di ọtún.

ÁDÙRÁ

Jesu Oluwa, ran mi lọwọ lati gba ọ laaye ninu aginjù ati aṣalẹ ayé mi, ki n le gba òmìnira pípé. Amin

BIBELI KIKA: Isaya 40:3-5

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *