PREREQUISITES TO RECEIVING YOUR HEART DESIRE
THE SEED
“Trust in the LORD and do good; dwell in the land and enjoy safe pasture. Take delight in the LORD, and he will give you the desires of your heart.” Psalms 37:3-4 NIV
Firstly, according to the above scripture, we need to trust God. We can only trust God when we know God, accept Jesus as our Lord and Saviour, and have a meaningful relationship with Him. When we trust God, we want to do good. We do good by accomplishing our purpose in life and being kind to other people.
Secondly, there’s a location, an area or destination for us in God’s plan. Until we get there, we might find it difficult to enjoy God’s safe pastures. Safe pasture represents the unceasing provision of God for us to live our lives in joy, peace, and righteousness.
Lastly, to have our desire in the Lord means that we must submit such desire to God and measure it with His own desire for us. This can only be achieved by taking delight in God, maintain an uninterrupted relationship with the Lord Jesus, studying the scriptures, listening to the Holy Spirit’s directions, and doing all things for Christ’s sake and not for our own gain. Joseph is a typical example. He trusted God enough to keep his relationship with God by not doing wrong. Eventually, Joseph got to the palace where God’s good pasture awaited him. PRAYER
Lord Jesus, help me to trust you. Lead me to my land of good pasture and help me to continually take delight in You all the days of my life. Amen
BIBLE READINGS: Genesis 39, Genesis 41:41-44
AWON AMUYE LATI RI IFE OKAN RE GBA
IRUGBIN NAA
“Gbekele Oluwa ki o si maa se rere; maa gbe ile naa, ki o si maa huwa otito. Se inu didun si Oluwa pelu, yio si fi ife inu re fun o.” Orin Dafidi 37:3-4
Lakoko, gege bi eko ti a ka, a gbodo gbeke lepa Olorun.Nigbati a ba mo Olorun ni a to le gbeke wa le, gba Jesu ni Oluwa ati Olugbala re ki o si ni ibasepo ti o dan moran pelu re. Bi a ba fi aye wa le Olorun lowo, yio je ohun ti o rorun fun wa lati se rere. Nigbati a ba se ohun ti a ran wa saye lati se, ti a si tun se daradara si omonikeji, eyi ni sise rere. Ife Olorun ni wipe ki a se rere.
Ekeji, ibikan, agbegbe, tabi ibudo wa fun wa ninu ipinnu Olorun. Lai se pe a de ibe tabi ki a gbe nibe, o see se ki o ma rorun fun wa lati jegbadun papa oko tutu ti Olorun ti pese sile fun wa. Papa oko tutu tumo si ipese Olorun fun wa ti ko ni opin, pe ki a le lo aye wa ninu ayo, alaafia ati ododo.
Lakotan, lati ni ife okan re ninu Olorun tumo si pe a ni lati jowo iru ife bee fun Olorun ki a si wo bi o ba ife Olorun fun aye wa mu. Eleyi seese nigbati a ba ni inu didun si Olorun, ki a ni ife ti ko ni abuja sii ki a baa le maa wa ni irepo pelu Jesu Oluwa. Nipa kika Bibeli, fifi eti si itoni Emi Mimo ati sise ohun gbogbo nitori Kristi, lai kin se fun ere tiwa. Josefu je apere, o gbeke le Olorun to bee ti o fi pa ibasepo ti o dara mo pelu re nigbati o ko lati se ibi ti o de baa, o gbagbo wipe Olorun wa pelu re, nigbeyin, Josefu de Aaafin nibiti papa oko tutu ti Olorun ti pese fun wa. ADURA: Jesu Oluwa, ran mi lowo lati gbeke le o, dari mi si ile papa oko tutu mi, ki o si ran mi lowo lati maa ni inu didun ninu re ni ojo aye mi gbogbo. Amin.
BIBELI KIKA: Genesis 39, Gen 41:41-44