PURPOSE PRESERVES

THE SEED

“And he said unto them, Go ye, and tell that fox, Behold, I cast out devils, and I do cures today and tomorrow, and the third day I shall be perfected.” – Luke 13:32

Jesus knew His divine purpose and was focused on completing it. When warned about Herod’s threat, He continued His mission with confidence, demonstrating that a life aligned with God’s purpose is preserved and directed. As God’s children, we too must understand and pursue our divine assignments. Purpose protects us from being wasted or misdirected by chance, fear, or circumstances. Walking in God’s purpose ensures that we achieve what He intended for our lives and live meaningfully in every moment.

 

BIBLE READINGS:  Luke 13:31–35 (KJV)

PRAYER: Lord, help me to walk faithfully in the purpose You have assigned me. May I never miss my divine calling, in Jesus’ name. Amen.

 

IDI IWASAYE A MAA PANIMO

IRUGBIN NAA

O si wi fun wọn pe, Ẹ lọ, ki ẹnyin si sọ fun kọ̀lọkọlọ nì pe, Kiyesi i, emi nlé awọn ẹmi èṣu jade, emi nṣe dida ara loni ati lọla, ati ni ijọ kẹta emi o ṣe aṣepe. Luku 13:32

 

Jesu mo idi ti a fi ran wa latorun, O si fokan si lati se ni asepe. Nigbati won kilo fun nipa ihale Herodu, O tesiwaju ninu ise Re pelu igboya, O nfihan wipe aye ti o wa ni ibamu pelu eto Olorun ni a pamo ti a si ndari. Gege bi omo Olorun, o gbodo ye awa naa, ki a si lepa lati se ise ti a ran wa latorun. Idi iwasaye wa a maa pawamo kuro ninu sise lasan, tabi ikuna, eru tabi awon isele. Ririn ninu eto Olorun maa mu ki a le se  ohun ti O ti pinnu fun aye wa, ki a si le gbe igbe aye to ni itumo ni igba gbogbo.

 

BIBELI KIKA: Luku 13:31-35

ADURA: Oluwa, ranmi lowo lati le fi otito rin ninu ise ti o firan mi. Mase je ki n padanu ipe mi ni oruko Jesu. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *