Put On The Full Armor

Ammor of God Wall Chart

THE SEED
Therefore put on the full armor of God, so that when the day of evil comes, you may be able to stand your ground, and after you have done everything, to stand. Ephesians 6:13

We have to be equipped with all the pieces of armor that God has provided for us in order to walk faithfully on God’s path, on a daily basis. Without having the armor on, we would be unable to remain strong in our faith in God, knowing that our Lord always loves us and never forsakes us. The enemy does everything in his power to convince us that God allows the problems and tribulations in our lives because we do not deserve His love, therefore He does not love us anymore. Jesus, though 100% innocent, was rejected, mocked, imprisoned, tortured and even whipped almost to death and then crucified as a common criminal. And He still never doubted the love of the Father. Jesus endured tremendous rejection, pain and suffering and never gave up on us. He went through such terrible torment to save us, because He loved and continues to love us so much. Only by thinking in agreement with God’s Word can we be truly convinced of how much God loves us and be able to stop measuring His love for us based upon how good or bad things are going in our lives. The more we renew our minds according to God’s truth, the more firm we may stand after doing all that we can in our crises in Jesus we are victorious!

BIBLE READING: 2 CORINTHIANS 10:3-5

PRAYER: Glory and honor to Your holy Name Lord Jesus for all You suffered in my place. Thank You with all my heart for making me a victor and giving me authority in Your Name. Lord, please help me remember that I can always protect myself by putting on Your armor and that the Holy Spiritlives in me and is always ready to help me in Jesus name. Amen

Ẹ GBE GBOGBO IHAMỌRA ỌLỌRUN WỌ̀

IRUGBIN NAA
Nítorí náà, ẹ gbé gbogbo ihamọra Ọlọrun wọ̀, ki ẹyin ki ọ le duro tiiri sí ọjọ ibi nigbati ẹyìn ba sì tí ṣe ohungbogbo tán ki ẹ sí dúró. Éfésù 6:13

A ní láti pèsè gbogbo ìhámọ́ra tí Ọlọ́run pèsè fún wa láti lè máa rìn ní ọ̀nà òtítọ́ ní ọ̀nà Ọlọ́run lójoojúmọ́. Láìsí ìhámọ́ra, a kì yóò lè dúró gbọn-in nínú ìgbàgbọ́ wa nínú Ọlọ́run, ní mímọ̀ pé Olúwa wa ní ifẹ̀ wa nígbà gbogbo tí ki yíó sì kọ̀ wá. Ọta n ṣe ohun gbogbo ni agbara rẹ lati fi da wa loju pe Ọlọrun gba awọn iṣoro ati awọn ipọnju laaye ninu igbesi aye wa nitori a ko yẹ fun ifẹ Rẹ: nitorinaa ko fẹran wa mọ.Jesu tilẹ jẹ alaiṣẹ, ti a kọ sílẹ, eniti a pẹgàn, ti a fi sinu tubu , a jẹ ẹ níyà a na a titi dé ojú iku, a kàn mọ igi agbelebu pẹlu awọn ọdaràn lásán. Sibẹ ko ṣe iyemeji nipa ifẹ bàbá Rẹ̀. Jesu farada ìkọ silẹ nla, irora ati ijiya, ko tori eyi kọ wà silẹ.O la iru ijiya ti o buru yi ja lati gba wa la nitori pe o nifẹ wá o sí tẹsiwaju lati nifẹ wa pupọ.Nipa ironu wa ti o ni ibamu pẹlu ọrọ Ọlọrun ni a le ni idaniloju nitootọ bi Ọlọrun ṣe fẹran wa pupọ: ki a si d’awọ wiwọn ifẹ Rẹ si wa. Lori bí ohun rere tabi buburu ti n la kọja ninu igbesi aye wa. Bi a ti ṣe nsọ ọkan wa di titun gẹgẹ bi otitọ Ọlọrun, bẹ ẹ̀ ni a le duro lẹhin ṣiṣe gbogbo ohun ti a le ṣe ninu awọn rogbodiyan wa ninu Jesu a di aṣẹgun!

BIBELI KIKA: Kọrinti Keji 10:3-5

ADURA: Ògo ati ọlá fún orúkọ mímọ́ rẹ Jesu Oluwa fún gbogbo ohun tí o jìyà ní ipò mi. Mo dupẹ pẹlu gbogbo ọkan mi fun ṣiṣe mi ni asegun ati fifun mi ni aṣẹ ni aṣẹgun ni Orukọ Rẹ. Oluwa, jọwọ ran mi lọwọ lati ranti pe mo le daabobo ara mi nigbagbogbo nipa gbigbe ihamọra Rẹ wọ ati pe Ẹmi Mimọ wa ninu mi ati pe o ṣetan nigbagbogbo lati ran mi lọwọ ni orukọ Jesu. Amin

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *