THE SEED
“Look, I am coming soon! My reward is with Me, and I will give to each person according to what they have done.” — Revelation 22:12 NIV
Just as families eagerly await a loved one’s return, we must eagerly await the return of Jesus Christ. His promise is sure, and His coming is certain. We must live daily with readiness — watching, praying, and staying pure in heart. Unpreparedness will be costly. All religious activity without readiness is empty before God. Stay alert, walk in righteousness, and let your heart be positioned to welcome the King of glory.
BIBLE READINGS: Matthew24:36–44
PRAYER: Lord, guide my life to remain in
a state of readiness for Your return. Amen.
MURA SILẸ FÚN IPADABỌ RẸ̀
IRUGBIN NAA
“Kíyèsí èmi nbọ kankan; èrè mí sí mbẹ pèlụ́ mí, láti sán án fún olúkúlùkù gẹgẹbi iṣẹ́ rẹ yió tí rí” ÌFIHÀN 22:12
Gẹgẹ bí àwọn ìdílé ṣe ń fi inagà dúró de ìpádà́bọ àwọn olólùfẹ wọn, a gbọ́dọ fi ìnàgà dúró dè ìpadàbọ̀ Jésù́ Kristi. Ileri R̀ ẹ daju, Wiwa Rẹ si daju. A gbọdọ̀ gbé ìgb̀é ayé ìmúrasílẹ pẹlú ni ojoojumọ — nipa ṣísọnà, gbígbàdú̀̀rà,̀ àti dídúró ṕ ẹlú ọkàn míḿ ọ. Àìmúrasílẹ yíò mu ìdààm̀ ú to pọ lọwọ .
Gbogbo iṣẹ̀ ẹsin laisi imurasilẹ jẹ ò fò niwá ju Ọlọrun. Ẹ ṣọra, ẹ máa rìn ní òdodo, kí ẹ sì jẹ kí ọkàn yín d́ úró láti kí Ọba ògo káàbọ̀ .
BIBELI KIKA: Mátíù 24:36–44
ADURA: Oluwa, dari aye mi lati duro ni ipo imurasilẹ fun ipadabọ Rẹ. Amin.