Ready To Sail

THE SEED
“Those who were foolish took their lamps and took no oil with them, 4 but the wise took oil in their vessels with their lamps.” Matthew 25:3-4

Before a ship sets sail, it is the sailor’s duty to check the ship and make sure features such as engines, mapping system, safety jackets etc. are working correctly for a safe voyage. If anything is found faulty, he must fix it. Likewise, a wise believer must check his spiritual life and ensure he is spiritually ready to face the new year. To be prepared means checking specific areas of your spiritual life such as prayer, meditation, stewardship, fellowship, evangelism; and making sure you have them in the right measure for a fruitful year. This was the wisdom of the five virgins who had extra oil for their lamp. Every year is always filled with twists and turns; only those who are spiritually prepared will weather the storm. In Luke 14 vs 28, Jesus emphasized on the need to plan and prepare as a requirement for a successful spiritual journey. Those who fail to plan are certainly planning to fail. Now is the time to reflect on where you are lacking in your spiritual life and take necessary steps to reposition yourself for a safe voyage in 2024.

BIBLE READING: Matthew 25: 1-13, Luke 14:25-33

PRAYER: Father, help me to prepare for the journey ahead of me this year, so that I may successfully sail into the blessings you have planned for me.

MURA IRIN AJO

IRUGBIN NAA
“Àwọn tí wọ́n jẹ́ aláìgbọ́n gbé fìtílà wọn ṣùgbọ́n wọn kò mú epo kankan lọ́wọ́. Àwọn ọlọ́gbọ́n mú epo sínú kólòbó lọ́wọ́ pẹ̀lú fìtílà wọn. Nígbà tí ọkọ ìyàwó pẹ́, gbogbo wọn tòògbé wọn sì sùn.” Luku 14: 25-33

Ki oko to bere irin ajo, ojuse awako ni lati ye oko naa wo boya awon nkan bii èrǫ, atónà, jákétì ààbò ati bebelo, wà ni dede fun irin ajo naa. Bi o ba si ni oun kan ti ko sise daradara, o ni lati rii wipe o tunse. Bakannaa, onigbagbo ologbon ni lati yę igbe aye emi re wo ki o si rii daju wipe oun mura irin ajo odun yii. A ni lati mura nipa awon nkan bii adura, àsàrò, ise isin, idapo emi ati pipolongo ihinrere; ki o si ri wipe gbogbo re kujuwon fun siso eso rere ninu odun naa. Eyi farape ogbon awon wundia maarun ti won mu epo sinu kolobo won. Gbogbo odun lo ni ewu tire; awon to ba si mura ninu emi nikan lo le laaja.Ninu Luku 14 vs 28, Jesu fi idi re mule wipe ìmúra pon dandan fun irin ajo emi. Eni to ba kùnà lati mura n mura lati kùnà. Akoko niyii lati ronu ibi to ku die kaato si ninu igbe aye emi re, ki o si se atunse ti o to fun àrìnyè ninu odun 2024.

BIBELI KIKA: Matiu 25:1-13, Luku 14: 25-33

ADURA: Baba, ran mi lowo lati mura fun irinajo odun yii, ki emi le rin wo inu Ibukun ti Iwo ti seto fun mi.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *