2nd REST API post

Beware of Bad Company

THE SEED

…bad company corrupts good character. – 1 Cor 15:33

Walking with bad company, someone of different opinion about your Christian life, can easily draw you back to the world and make you develop cold feet towards your faith in the Lord. Apostle Paul gave a strict warning about this to the Corinthians. He sternly warned them not to be yoked together with unbelievers. As children of light, we should not be enticed by things and relationships of the world. Our fellowship must be in the Lord with brethren of same faith that can encourage us in times of challenges, pray with us, show us love in the Lord and help us to be back on our feet when we fall short or go astray.

So, if we totally believe beyond any doubt that by God’s grace, we are born again, justified, saved and redeemed by the blood of Jesus Christ, then we must watch out, not to be yoked with people that don’t share our faith and experience in the Lord Jesus. Yes, they might be close relatives, superior or colleagues at work, neighbours, and childhood friends. We can’t renounce them or be unfriendly to them, but wisdom is the principal thing. Let’s depend on the Holy Spirit for wisdom to navigate our way with them in love; but remember that if the Bible says “…bad company corrupts good character”, it does indeed.

PRAYER

Lord Jesus, I ask for wisdom to deal with unbelievers on my path to show them the love of Christ but never get mixed up with their ways. Amen

BIBLE READINGS: 2 Corinthians 6:14-18 

SORA FUN EGBE KEGBE

IRUGBIN NAA

Biba egbe kegbe rin, eniti kii se onigbagbo kanna pelu re le fa o pada sinu aye ki o si mu ki igbagbo re ninu Olorun rewesi. Paul Aposteli kilo fun awon ara Korinti, o kilo fun won gidigidi wipe ki won mase fi aidogba dapo mo awon alaigbagbo. Gege bi omo imole, a ko gbodo je ki won fi etan tabi ibare aye gba wa lo. Ipejo po wa gbodo je ti Olorun pelu awon ara ninu igbagbo kan naa ti o le ran wa lowo ni igba iponju, gbigba adura pelu wa ati fifi ifehan si wa ninu Olorun tabi ki won ran wa lowo lati pada sori ese wa nigbati a ba subu tabi ti a sako lo.

Notorinaa, bi a ba gbagbo lai se iyemeji wipe nipa oore ofe Olorun, wipe a ti di atunbi, ati da walare, a ti gba wa la, a si ti ra wa pada nipa eje Jesu Kristi, a gbodo kiyesara ki a ma baa dapo, lepo, gbimo po, wo inu tabi jade pelu awon ti ko ni iru igbagbo ati iriri wa ninu Jesu Oluwa. Lotito, won le je ebi, oga tabi elegbe wani ibi ise, alabagbe, ore ati kekere wa, ti a ko le ko sile tabi ki a ma ba sore mo, sugbon ogbon ni ipinlese ohun gbogbo, e je ki a gbeke le Emi mimo fun ogbon ti a o fi ba won lo pelu ife. Sugbon ranti wipe bi Bibeli ba so wipe ‘egbe buburu n ba iwa rere je’, otito ni.

ADURA

Jesu Oluwa, mo beere fun ogbon lati ba awon alaigbagbo ni ona mi gbe pelu ife, ki n le fi ife Kristi han won, sugbon ki n mase dapo mo ona won. Amin.

BIBELI KIKA: II Korinti 6:14-18

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *