RETURN TO YOUR FIRST LOVE

THE SEED
“But this I have against you; you do not love me now as you did at first…” — Revelation 2:4 GNB
Love is the greatest commandment of all (Matthew 22:37–38). The Ephesian church worked hard for God, stayed faithful, and overcame trials, but their love for Him had grown cold. Jesus considered this a sin and called them to repentance. Your first love is not just a feeling but a daily devotion and intimacy with God that fuels obedience and joyful service. When love is your foundation, your service becomes meaningful, and your worship becomes alive. God measures everything we do for Him through the lens of love. Service without love is empty before Him. Your first love is the passionate, personal devotion that keeps your relationship with God alive. Return to it.
BIBLEREADINGS: Revelation2:1–5
PRAYER: Heavenly Father, teach me what love means to You so I can walk in it always. Amen.

PADA SI IFE AARO RE
IRUGBIN NAA
Ṣugbọneyinimoriwisiọ,pe,iwọtifiifẹrẹ iṣaju silẹ. ÌFIHÀN 2:4
Ife ni ofin to julo ninu gbogbo ofin. (Matiu 22:37-38). Ijo Efesu sise takuntakun fun Olorun, won je olooto, won bori isoro sugbon ife won tutu. Eyi ni Jésù ka si ese ti o fi pe won si ironupiwada. Ife akoko kii se imolara nikan bikose ifokansin ati sisunmo Olórun eyi ti n s’okunfa igboran ati isin alayo. Ti ife ba je ipinle re, ise isin re a ni itumo, iyin re a si wa láàyè.
Olórunamaagbeohuntiabasefúnunle osuwon nipase ife. Ise isin laisi ife bọ́ si òfo loju Re. Ife akoko re ni ìsìn ti o ni itara pelu ìfaraeni jì, eyi ti yoo mu ibasepo re pelu Olórun munadoko. Pada si ife yii.
BIBELI KIKA: Ifihan 2:1-5
ADURA: Baba mi Orun, kó mi ni ohun ti ife jesiOkinbalerinninurèniigbagbogbo. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *