Spirit Of Excellence

THE SEED
“…it seemed good to me also, having had perfect understanding of all things from the very first, to write to you an orderly account, most excellent Theophilus” Lk. 1:3 NKJV

Do everything you do to the best of your ability. Do everything with a spirit of excellence. So your work can speak for you long after you are gone. Luke, the Doctor set out to explain Christianity to his friend Theophilus. He wrote two letters; the Gospel of Luke and Acts of the Apostles. However, he did such an excellent job of documenting the events, together with dates and eyewitness accounts, that the early church by the inspiration of the Holy Spirit included these ‘letters’ in our bible today. How incredible! Give your best all the time, you don’t know where it will go. Moreover, others might have done what you’re doing now just like Dr Luke experienced but your attention to detail in excellent may give you the edge over others, don’t allow how far other people have gone or the things they didn’t do be a yardstick for your excellent performance, don’t settle for little when you have the opportunity to make a huge difference. Be excellent in all that you do!

PRAYER
Heavenly Father help me to always give my best no matter what I do. To work according to Your expectations, in Jesus’ name Amen.
BIBLE READINGS:  Luke 1: 1 – 3 NKJV

   EMI YIYEGE

IRUGBIN NAA
“…Ó sì dára lójú mi pẹ̀lú, nígbà tí mo ti ní òye pípé nípa ohun gbogbo láti ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀, láti kọ̀wé àkọsílẹ̀ tí ó wà létòlétò sí ọ, Téófílosì ọlolá jù lọ.” Luuku 1:3 KJV

Gbogbo oun ti o ba se, se e pelu gbogbo ipa re. Ṣe ohun gbogbo pẹlu ẹmi aseyege. Ise re yio ma a so nipa re lehin ti o ti fi aye yi síle. Luku, Dókítà náà gbéra láti ṣàlàyé ẹ̀sìn Kristẹni fún ọ̀re rẹ̀ Teofilu. O kọ awọn lẹta meji; Ihinrere Luku ati Iṣe Awọn Aposteli. Bí ó ti wù kí ó rí, ó ṣe ise nla takuntakun kan nipa Kiko awon isele síle, pelu awon ojo ti o sele àti awon isele afojuri, eyi ti ijo akoko nípasẹ̀ ìmísí Ẹ̀mí Mímo ti a ko síle sínú Bibeli wa lónìí. O je iyanu! Sa gbogbo ipa re ni gbogbo ígba Nítorí Iwo ko mo ibi ti o le de.Pẹlupẹlu, awọn miiran le ti ṣe ohun ti o n ṣe ni bayi gẹgẹ bi Dokita Luku ti ni iriri ṣugbọn akiyesi rẹ si awọn alaye ni pipe le mu o tayo ju awon akegbe re. Mase Tori pe awon ènìyàn ti fio síle lo tabi nitoripe won ko se awon nkankan ki o waje osuwon fun o Lati sise takuntakun. Ma se se ise kekere nigba ti o ni anfaani Lati se oun nla ti o lamilaka. Je pipe nínú oungbogbo ti o ba se.

ADURA
Bàbá Ọ̀run ràn mí lowo láti máa fi gbogbo agbára mi ṣe ohun gbogbo ti mo ba n se,Lati sise gege bi ireti Re, ni oruko Jesu Amin.
BIBELI KIKA: Lúùkù 1:1-3 NKJV

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *