THE SEED
Go ye therefore, and teach all nations, baptizing them in the name of the Father, and of the Son, and of the Holy Ghost: Matthew 28:19
While many of us may never consider ourselves to be exceptional wordsmiths, we have all served as teachers at some point. Every time we parent, encourage, enlighten, advise, support, challenge, or tell someone about how God has worked in our lives, we are teaching them something. Every activity the church engages in—worship, management, service, and outreach—teaches, and each member of the church serves as both a teacher and a student. In Ephesians 4:11, Our Lord Jesus Christ placed instruction above the fivefold ministry. Although, prophets are also excellent, Jesus Christ did not train His disciples to be prophets; rather, He prepared them to preach His Word. This should show us that the role of the teacher is more significant and higher than the roles of the apostle, prophet, evangelist, and pastor. To foster comprehension in both new converts and even current members of the body of Christ, teaching from the Holy Scriptures is necessary. Teaching educates, leads, directs, counsels, comforts, increases, and keeps the church’s membership. Let the world take a lesson from the church and give educators in society their due respect.
PRAYER
O Lord, give the spirit to know more of your teachings and also be teacher of your word. Amen.
BIBLE READINGS: Mathew 28:1-20
OLUKO ORO
IRUGBIN NAA
Nitori naa e lo, e ma ko orile-ede gbogbo, ki e si ma baptisi won li oruko Baba, ati ni ti Omo, ati ni ti Emi Mimo Matteu 28:19
Nigbati opolopo wa ko ri ara wa bi oluko ti o kujuwon, a ti je oluko ni igba kan ri. Ni gbogbo igba ti a ba obi, ti a ba gbani ni yanju, tan imole si ohun ti o ru ni loju, sise ati lehin, pe ni nija tabi so fun eniyan nipa bi Olorun se sise ni aye wa, a n ko ni ni. Gbogbo ise ti ijo n se bi – ijosin, abojuto, ise ati ipolongo ihinrere – ma n koni, gbogbo omo ijo si je oluko ati akeko. Ni Efesu 4:11, Oluwa wa Jesu Kristi pase lori ise iranse marun ti o wa. Bi o ti le je wipe, Woli dara, Jesu Kristi ko ko awon omo ehin re lati je woli, sugbon o ko won lati waasun oro re. Eyi ye ki o fi han wa pe ise Oluko se Pataki bi ise awon Aposteli, Woli, ajihinrere ati Oluso aguntan. Lati je ki oye ye awon ti o ti je omo ijo ati awon ti o se darapo mo ijo, kiko eko lati inu iwe mimo se Pataki. Eko ma n fi oye yeni, dari, tan ni sona, gbani niyan ju, tun eniyan ninu, mu idagbasoke wa ati mu awon omo ijo duro sinsin. Jeki araye ko eko lara ijo Olorun ki a si fun awon Oluko ninu awujo ni owo ti o to.
ADURA
Oluwa, fun mi ni emi lati mo nipa eko re ati lati je oluko oro re. Amin.
BIBELI KIKA: Matteu 28 :1-20