THE AUTHORITY OF GOD’S WORD

THE SEED

“So shall my word be that goes forth from my mouth; It shall not return to Me void, but it shall accomplish what I please, and it shall prosper in the thing for which I sent it.” – Isaiah 55:11

God’s Word carries absolute authority. The universe operates under laws, and His Word is the ultimate law—unchanging, impartial, and powerful. Believers can rely on God’s promises because His Word will always accomplish its purpose. Understanding that God is a respecter of His Word empowers us to hold fast to His promises, no matter the circumstances. His Word governs and accomplishes what He intends. When we apply it with faith, we experience its full power in our lives.

 

BIBLE READINGS:  Isaiah 55:8–11 (KJV)

PRAYER: Heavenly Father, I choose to believe and stand on Your Word in every situation. Let Your Word accomplish its purpose in my life, in Jesus’ name. Amen.

 

 

ASE ORO OLORUN

IRUGBIN NAA

Bẹ̃ni ọ̀rọ mi ti o ti ẹnu mi jade yio ri: kì yio pada sọdọ mi lofo, ṣugbọn yio ṣe eyiti o wù mi, yio si ma ṣe rere ninu ohun ti mo rán a. Isaiah 55:11

 

Ase nla ni o wa ninu Oro Olorun. Gbogbo agbaye nsise labe ofin, Ore Re si ni ofin to ga julo. O je ofin ti kii yipada, ki ise soju isaju, o si lagbara. Onigbagbo le simi le awon ileri Olorun nitori Oro Re yoo se eyi ti o wu U. Nigbati a ba ni oye wipe Olorun gbe Oro Re ga, yio ranwalowo lati le di ileri Re mu, ohunkohun to wu ko le de. Oro Re nsakoso, o si nmu eyi to wu U se. Nigba ti a ba fi igbagbo gbe, a o ri agbara Oro Re ninu aye wa.

 

BIBELI KIKA: Isaiah 55:8-11

ADURA: Baba mi Orun, mo pinu lati gbagbo, ki nsi duro lori Oro Re ninu ohun gbogbo. Je ki Oro Re se eyi ti O ran lati se ninu aye mi, ni oruko Jesu, Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *