THE BALM OF HEALING

THE SEED

“Is there no balm in Gilead; is there no physician there? Why then is not the health of the daughter of my people recovered?” – Jeremiah 8:22

God’s plan for His children has always included health and wholeness—spirit, soul, and body. In the Garden of Eden, there was no sickness. Sin introduced disease into the world. Today, illnesses and pandemics remind us of this reality. Yet God’s promise through Jesus Christ is that by His stripes we are healed. Healing comes when we believe His Word, confess our sins, and live in obedience. God’s Word is truth and power, and it brings restoration to every part of our lives. Do not allow sin or negligence to open doors for disease; hold firmly to the Balm of Gilead—Jesus Christ.

 

BIBLE READINGS:  3 John 1:2 (KJV)

PRAYER: Lord, I confess my sins and receive Your healing in every area of my life. Restore me in spirit, soul, and body, in Jesus’ name. Amen.

 

ORORO IWOSAN

IRUGBIN NAA

Kò ha si ojiya ikunra ni Gileadi, oniṣegun kò ha si nibẹ? ẽṣe ti a kò fi ọ̀ja dì ọgbẹ́ ọmọbinrin enia mi. Jeremiah 8:22

 

Ero Olorun fun awon omo Re ni ilera, ilera emi, okan, ati ara. Ninu ogba Edeni, ko si aisan kankan. Ese ni o mu aisan wonu aye. Loni, aisan ati ajakale arun ni o nranwa leti. Sibe, ileri Olorun nipase Jesu Kristi ni wipe, nipa ina Re ni a muwa larada. Imularada nwa nigbati a ba gba Oro Re gbo, ti a jewo ese wa, ti a si ngbe ninu igboran. Oro Olorun ye, o je otito, o si lagbara, o si nmu imupada sipo ba gbogbo ona aye wa. Mase gba ese tabi aikasi laaye lati si ilekun fun aisan. Di Ororo Giliadi mu sinsin, eyi ti nse Jesu Kristi.

 

BIBELI KIKA: III JOHANNU 1:2

ADURA: Oluwa, mo jewo ese mi, mo gba iwosan Re ni gbogbo ona aye mi. Mumi pada si ipo ninu emi, okan ati ara ni oruko Jesu. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *